Yusuph Adebola Olaniyonu jẹ́ akọroyin, agbẹjọ́rò àti alábòójútó, tó ń ṣiṣẹ́ bíi olùdámọ̀ràn pàtàkí lórí Media àti ìpolówó sí Ààrẹ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ Naijiria, Bukola Saraki.[1]

Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Yusuph Olaniyonu ni wọ́n bí sí ìlú Èkó ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje, ọdún 1966. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Ogun State Polytechnic, Abeokuta (èyí tí a mọ̀ sí Moshood Abiola Polytechnic báyìí) láàrin ọdún 1983 sí 1988, ó sì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tó dára jù lọ láti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Mass Communication.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Office of the Senate President. "Saraki Appoints Ex-Senator as Special Adviser". Press Releases - Office of the Senate President. Retrieved 1 April 2018. 
  2. "UNVEILING AMOSUN'S CABINET". The Nigerian Voice. NBF News. Retrieved 1 April 2018.