Yvonne Ekwere
Yvonne Imoh-Abasi Glory Ekwere (bíi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1987) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Yvone Vixen Ekwere je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré, òun sì ni atọkun ètò Ẹ-Weekly lórí Silver bird Television.[1] Ó ti ṣe atọkun ètò lórí Rythm 93.7 Fm náà.[2][3]
Yvonne Ekwere | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Yvonne Imoh-Abasi Glory Ekwere 3 Oṣù Kẹta 1987 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Lagos State University |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008 – present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeVixen jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ni orile-ede Nàìjíríà, òun sì ní àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ méje, ìlú Èkó sì ni wọn bí sì. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Air force Primary School àti Holy Child College ni ìlú Èkó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Lagos State University, ní ibi tí ó ti kà ìwé imọ History and International Studies.[4]
Iṣẹ́
àtúnṣeRadio/Tv
àtúnṣeO bẹ́ẹ̀ rẹ sì ni ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ọdún 2008 ni ìgbà tí wọn fi ṣe atọkun fún eto Dance part lòri Rhythm 93.7 Fm.[5] Wọn gbà gẹ́gẹ́ bíi olóòtu fún eto E-Weekly lóri Silver bird Television. Ó ti ṣe Ifọrọwanilẹnuwo fún àwọn gbajúmọ ẹ̀yán bíi Olórí orile-ede Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan, ó sì ti ṣe atọkun fún eto bíi Most Beautiful Girl in Nigeria 2012. Ní oṣù kẹwàá ọdún 2015, ó dá ètò tiẹ̀ sílẹ̀, ètò na ń jẹ Drive Time with Vixen.[6]
Films and soaps
àtúnṣeYvonne tí kó pa nínú àwọn eré bíi 7 Inch Curve, Render to Caesar, Put a Ring on It àti Gidi Up .[7]
Ebun
àtúnṣeYear | Award ceremony | Prize | Result |
---|---|---|---|
2009 | Future Awards | TV Personality of the Year | Wọ́n pèé |
2010 | Wọ́n pèé | ||
FAB Awards | Wọ́n pèé | ||
2011 | Gbàá | ||
Future Awards | Wọ́n pèé | ||
ELOY Awards 2011 | Gbàá | ||
The Nigerian Events Awards | Best Event Coverage | Gbàá | |
2012 | City People Fashion Awards 2012 | Most Stylish TV Presenter of the Year | Gbàá |
2013 | 2013 Nigeria Entertainment Awards | TV Personality of the Year | Wọ́n pèé |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Kayode Badmus (3 March 2016). "Popular broadcaster, Yvonne Vixen Ekwere clocks 29 years". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2016/03/popular-broadcaster-yvonne-vixen-ekwere-clocks-29-years/. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Esho Wemimo (17 October 2014). "Yvonne Vixen Ekwere: My Ex Used Me To Get Famous". Pulse Nigeria. http://pulse.ng/celebrities/yvonne-vixen-ekwere-my-ex-used-me-to-get-famous-id3205278.html. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Maryjane Ezeh (3 March 2016). "Yvonne Vixen Ekwere Overdosed On Self-Love As She Celebrates Birthday (Photos)". nigeriafilms.com (The Nigerian Voice). https://m.thenigerianvoice.com/news/208118/yvonne-vixen-ekwere-overdosed-on-self-love-as-she-celebrates.html. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Yvonne Vixen Ekwere Biography". www.mybiohub.com. 3 March 2016. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Christian Agadibe (14 August 2016). "Fans stalk me for love –Yvonne Ekwere, radio presenter". The Sun Newspaper. http://sunnewsonline.com/fans-stalk-me-for-love-yvonne-ekwere-radio-presenter/. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ Adeola Adeyemo (24 March 2012). "BN Saturday Celebrity Interview: She’s Called "Vixen" For a Reason. Meet TV Presenter Yvonne Ekwere". BellaNaija. Retrieved 25 September 2016.
- ↑ "Toolz, OC Ukeje, Zainab Balogun, Ikechukwu, Adesua Etomi at "Gidi Up" Season 2 Premiere". BellaNaija. 22 June 2014. Retrieved 25 September 2016.