Yvonne Orji
Yvonne Anuli Orji (bíi ni ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1983) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Insecure ní ọdún 2016, èyí tí ó jé kí wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ tí Primetime Emmy Award àti NAACP Image Awards.
Yvonne Orji | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Yvonne Anuli Orji 2 Oṣù Kejìlá 1983 Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011–present |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Orji ni ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1983 sì ìlú Port Harcourt ni Ìpínlẹ̀ Rivers ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó sì dàgbà sì ìlú Lauren ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.[1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Linden Hall. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí George Washington University níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Liberal Arts. Ní ọdún 2009, ó lọ sí ìlú New York City láti ṣe iṣẹ́ aláwàdà.[2] Ní ọdún 2015, ó kó ipa Molly nínú eré Insecure.[3] Ní ọdún 2008, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Population Services International fún oṣù mẹ́fà lórílẹ̀ èdè Liberia. Ó jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ fún Jumpstart àti JetBlue.[4] Ní ọdún 2020, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí Outstanding Supporting Actress in a Comedy Series láti ọ̀dọ̀ Primetime Emmy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré Insecure.
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé eré | Ipa tí ó kó | Àfíkún |
---|---|---|---|
2011 | Love That Girl! | Njideka | Episode: "Head Shrunk" |
2013 | Sex (Therapy) with the Jones | Moshinda | Short film |
2016–present | Insecure | Molly Carter | 34 episodes |
2017 | Jane the Virgin | Stacy | 2 episodes |
2017 | Flip the Script | Ad Exec 1 | Episode: "Mad Woman" |
2018 | Night School | Maya | |
2019 | A Black Lady Sketch Show | Flight attendant | Episode: "Why Are Her Pies Wet, Lord?" |
2020 | Momma, I Made It![5] | Herself | HBO comedy special |
2020 | Spontaneous | Agent Carla Rosetti | |
TBA | Vacation Friends | Post-production |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "YVONNE ORJI". http://issuemagazine.com/yvonne-orji/#/.
- ↑ Davis, Allison P. (2016-10-10). "Molly From 'Insecure' Is Your New Favorite Single Lady". The Ringer. https://theringer.com/yvonne-orji-interview-insecure-904c39efe72#.xj298jdn9.
- ↑ Connley, Courtney (17 November 2018). "Yvonne Orji landed her role on HBO's 'Insecure' with no agent, no manager and zero acting experience". CNBC. https://www.cnbc.com/2018/11/16/yvonne-orji-landed-her-insecure-role-without-an-agent-or-a-manager.html. Retrieved 27 June 2020.
- ↑ UTA, Talent Agency. "Yvonne Orji, UTA Bio Page". Archived from the original on 2019-08-12. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Ani, Ivie (6 June 2020). "How Yvonne Orji Made It". Paper. Retrieved 6 July 2020.