Zafeeruddin Miftāhi (ọjọ kèjè,óṣu March 1926 – ọjọ ọkan lèèlọgbọn, óṣu March 2011) jẹ onimimọ ẹsin musulumi ati adajọ ilẹ India to jẹ Mufti of Darul Uloom Deoband ati arẹ̀ keji fun ilẹ kewu ti Fiqh[2]. Arakunrin naa ṣè akójọ ofin ẹsin ti Azizur Rahman Usmani ta n peni Fatāwa Darul Uloom Deoband ni iwọ didun mèjila to si tun kọ iwè bi Islām Ka Nizām-e-Masājid, Islām Ka Nizām Iffat-o-Asmat ati Tārīkh-e-Masājid.

Mawlāna, Mufti

Zafeeruddin Miftāhi
2nd President of Islamic Fiqh Academy, India
In office
2002 – 31 March 2011
AsíwájúMujahidul Islam Qasmi
Arọ́pòNematullah Azmi[1]
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí7 March 1926
Darbhanga, British India
(present day Bihar, India)
Aláìsí31 March 2011(2011-03-31) (ọmọ ọdún 85)
Alma materJamia Miftahul Uloom

Miftāhi jade ni Jamia Miftahul Uloom. Arakunrin naa jẹ ọmọ igbimọ ti ẹkọ Sunni ni ilè iwè giga musilumi ti Aligarh. Miftāhi sin ilè iwè Deoband fun ọdun maarun dinlogun pẹlu ofin ẹ́sin ẹgbẹrun lọna mẹwa[3].

Ìtan Ìgbèsi Àyè Zafeeruddin Miftahi

àtúnṣe

Zafeeruddin Miftāhi ni wọn bini ọjọ kèjè, óṣu March 1926 (ọjọ kèji lèèlogun ọṣu Sha'ban, ọdun 1344 AH) ni ilù Darbhanga[4]. Arakurin naa ka iwe rẹ̀ akọkọ lẹyin naa ni ilè iwè Madrasa Mahmudiya ni Terai, Nepal.

Zafeeruddin kẹẹkọ lori èdè larubawa ati Persia ni Madrasa Wāris al-Ulūm ni Chhapra lati ọdun 1933 de 1940. Arakunrin naa jade lati Jamia Miftahul Uloom ni ọdun 1940 de 1944 pẹlu Habib al-Rahman al-'Azmi ati Abdul Lateef Nomani[5].

Awọn ólukọ rẹ to ku ni Hussain Ahmad Madani, Sulaiman Nadwi, Minatullah Rahmani, Abul Hasan Ali Nadwi ati Muhammad Tayyib Qasmi[6].

Miftāhi died ku ni ọjọ kọkan lèèlọgbọn, óṣu March ni ọdun 2011. Wọn si ni ọjọ akọkọ, óṣu April, ọdun 2011[7].

Awọn ìṣẹ rẹ

àtúnṣe

Miftāhi ṣè akojọpọ ofin ẹsin ti Azizur Rahman Usmani, ti a mọ si Fatāwa Darul Uloom Deoband ni iwọ didun mèjila larin ọdun 1962 ati ọdun 1972[8].

Ọrọ rẹ lori iwè mimọ Qur'an ti akọlẹ rẹ jẹ Dars-e-Qur'ān ni o tẹ jade ni iwọ didun mẹwa. Arakunrin naa kọ itan nipa ìgbesi àyè Muhammad Qasim Nanautawi, Manazir Ahsan Gilani ati Muhammad Tayyib Qasmi[9]. Awọn iwè rẹ to ku ni[9];

  • Islām Ka Nizām-e-Masājid
  • Islām Ka Nizām Iffat-o-Asmat (Hijāb-o-Iffat az Dīdgah-e-Islām in Tehran).
  • Tārīkh-e-Masājid
  • Mashāhīr Ulama-e-Deoband
  • Darul Uloom: Qayām awr Iska Pas-e-Manzar
  • Darul Uloom: Ek Azeem Maktab Fikr
  • Nizām-e-Tarbiyyat (Ināyat al-Islām bi al-Tarbiyyat al-Atfāl)
  • Islām Ka Nizām-e-Hayāt
  • Jurm-o-Saza Kitāb-o-Sunnat Ki Roshni Mai
  • Islāmi Hukūmat ke Naqsh-o-Nigār
  • Islām ka Nizām-e-Amn

Awọn Itọkasi

àtúnṣe

Qasmi, Nayab Hasan (2013). "Mufti Zafeeruddin Miftāhi". Darul Uloom Deoband ka Sahāfati Manzarnāma (in Urdu). Deoband: Idara Tahqeeq-e-Islami. pp. 214–216.

  1. "Maulana Nematullah Azmi elected as president of Islamic Fiqh Academy". Two Circles. 31 May 2011. https://twocircles.net/2011may31/maulana_nematullah_azmi_elected_president_islamic_fiqh_academy.html. 
  2. "Mufti Zafeeruddin Miftahi, Mufti Darul Uloom, Passes Away in Darbhanga". DEOBAND ONLINE. 2011-03-31. Archived from the original on 2023-09-23. Retrieved 2023-09-14. 
  3. Miftahi, M.Z. (1993). Modesty and Chastity in Islam. Qazi Publishers and Distributors. ISBN 978-81-85362-35-9. https://books.google.com.ng/books?id=vNycnQAACAAJ. Retrieved 2023-09-14. 
  4. Amīni 2017, p. 929.
  5. Amīni 2017, p. 930.
  6. Amīni 2017, p. 922.
  7. Qāsmi 2011, p. 130.
  8. Stephens, J. (2018). Governing Islam: Law, Empire, and Secularism in Modern South Asia. Cambridge University Press. p. 76. ISBN 978-1-107-17391-0. https://books.google.com.ng/books?id=8glaDwAAQBAJ&pg=PA76. Retrieved 2023-09-14. 
  9. 9.0 9.1 Qāsmi 2011, pp. 219–223.