Zainab Momoh (tí a bí ní ọjọ́ kẹta, oṣú kọkànlá, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílè-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó kópa nínú ìdíje ti ilè Africa ní ọdún 2017 àti 2018, ó sì wà lára àwọn tó gbégbá orókè.[2][3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

àtúnṣe

Ìdije ti ilẹ̀ Africa

àtúnṣe

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2018 Salle OMS Harcha Hacéne,

Algiers, Algeria

  Peace Orji   Doha Hany

  Hadia Hosny

11–21, 11–21   Bronze
2017 John Barrable Hall,

Benoni, South Africa

  Dorcas Ajoke Adesokan   Doha Hany

  Hadia Hosny

4–21, 26–24, 18–21   Bronze

Ìdíje àwọn ọ̀ọ́ ti ilè Africa

àtúnṣe

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2014 Otse Police College,

Gaborone, Botswana

  Kingsley Nelson   Georges Paul

  Aurélie Allet

13–21, 14–21   Bronze

Ìdíje gbogboogbò ti BWF

àtúnṣe

Àdàpọ̀

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2017 Lagos International   Ramatu Yakubu   Thilini Hendahewa

  Kavidi Sirimannage

8–21, 5–21 Runner-up
2017 Côte d'Ivoire International   Peace Orji   Simran Singhi

  Ritika Thaker

11–21, 14–21 Runner-up

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Players: Zainab Momoh". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 14 October 2016. 
  2. "Paul and Adesokan; Africa's Best Juniors". bcabadminton.org. Badminton Confederation of Africa. Retrieved 14 October 2016. 
  3. "Host Win Women's and Mixed Doubles". bcabadminton.org. Badminton Confederation of Africa. Retrieved 14 October 2016.