Peace Orji
Peace Orji (tí a bí ní ọjọ́ kogún, oṣù kejìlá, ọdún 1995) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1] Ó kópa nínú ìdíje ti ilẹ̀ Africa ní ọdún 2019, ó sì gba ẹ̀bùn fún ipò alákọ̀ọ́kọ́. Ó sì gba ẹ̀bùn fún ipò kẹta nínú ìdíje àdàlú tí wọ́n ṣe.[2][3]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
àtúnṣeEré ti ilẹ̀ African
àtúnṣeÀdàlú ẹ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Ain Chock Indoor Sports Center,
Casablanca, Morocco |
Enejoh Abah | Adham Hatem Elgamal | 18–21, 21–13, 19–21 | Bronze |
Àṣeyọrí ti ilẹ̀ African
àtúnṣeÀdàlú ẹ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Alfred Diete-Spiff Centre,
Port Harcourt, Nigeria |
Augustina Ebhomien Sunday | Amin Yop Christopher | 16–21, 14–21 | Bronze |
2018 | Salle OMS Harcha Hacéne,
Algiers, Algeria |
Zainab Momoh | Doha Hany | 11–21, 11–21 | Bronze |
Àdàlú ẹ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Alfred Diete-Spiff Centre,
Port Harcourt, Nigeria |
Enejoh Abah | Koceila Mammeri | 21–15, 16–21, 18–21 | Silver |
2018 | Salle OMS Harcha Hacéne,
Algiers, Algeria |
Enejoh Abah | Koceila Mammeri | 17–21, 21–15, 12–21 | Silver |
Ìdíje ti àgbáyé ti BWF
àtúnṣeÀdàlú ẹ̀
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2017 | Benin International | Uchechukwu Deborah Ukeh | Dorcas Ajoke Adesokan | 18–21, 21–16, 12–21 | Runner-up |
2017 | Côte d'Ivoire International | Zainab Momoh | Simran Singhi | 11–21, 14–21 | Runner-up |
Àdàlú ẹ̀
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2017 | Benin International | Enejoh Abah | Emmanuel Donkor | 21–14, 21–11 | Winner |
2017 | Côte d'Ivoire International | Enejoh Abah | Gideon Babalola | Walkover | Winner |
Àwọn ìtọ́kasi
àtúnṣe- ↑ "Player: Peace Orji". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 5 July 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedra
- ↑ Shittu, Mudashiru (30 August 2019). "2019 African Games: Nigeria Badminton Scorecard". wildflowers.com.ng. Archived from the original on 5 July 2020. Retrieved 5 July 2020.