Abeni jẹ́ eré ìfẹ́ Nigerian-Beninese onípa méjì tí ọdun 2006 tí Tunde Kelani ṣe àkoso rẹ̀.[1][2] Ó ṣe àfihàn ìpinyà ti ó wà ní àwùjọ èyí tí ó jẹ́ abayọrisi ìgba ìkónilẹru, bótilẹ̀jẹ́pe Benin àti Nigeria fẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́.[3]

Abeni
Fáìlì:Movie poster of Abeni.jpg
AdaríTunde Kelani
Òǹkọ̀wéYinka Ogun
François Okioh
Àwọn òṣèréJide Kosoko
Kareem Adepoju
Abdel Amzat
Bukky Wright
Ilé-iṣẹ́ fíìmùDove Media, Laha Productions
Mainframe Film and Television Production
OlùpínMainframe Film and Television Productions
Déètì àgbéjáde
  • Oṣù Kẹta 31, 2006 (2006-03-31)
Àkókò98 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
Benin
ÈdèYoruba
French

Abeni jẹ́ ojúlówó ìtan òṣère Abeni tí ó jẹ́ ọmọ olówó. Ó pàdé Akanni tí òún wá láti ìdílé bọ̀ńkẹ́jẹ́. who hails from a more modest background. Wọ́n ti ṣe ìdána láti ṣègbéyàwó pẹ̀lu ẹlòmíràn lọ́tọ̀ọ̀tọ̀, ṣùgbọ́n ìpàde wọ́n yí ètò padà.

Àwọn Akópa

àtúnṣe
  • Kareem Adepoju gẹ́gẹ́ bíi Baba Wande
  • Abdel Hakim Amzat gẹ́gẹ́ bíi Akanni
  • Sola Asedeko gẹ́gẹ́ bíi Abeni
  • Amzat Abdel Hakim gẹ́gẹ́ bíi Akanni
  • Jide Kosoko gẹ́gẹ́ bíi Abeni's father
  • Bukky Wright
  1. Akande, Victor (2007-04-28). "Movie Review: Abeni". The Nation (Nigeria). Archived from the original on 2014-10-31. Retrieved 31 October 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Iyiola, Amos Damilare (2021-01-17). "Code-Switching, Code-Mixing and Code-Conflicting in Abeni by Tunde Kelani" (in en). KIU Journal of Humanities 5 (4): 169–174. ISSN 2522-2821. https://www.ijhumas.com/ojs/index.php/kiuhums/article/view/1112. 
  3. Ogunleye, Foluke (2014-03-17) (in en). African Film: Looking Back and Looking Forward. Cambridge Scholars Publishing. ISBN 978-1-4438-5749-9. https://books.google.com/books?id=2msxBwAAQBAJ&dq=Abeni+2006+Tunde+kelani&pg=PA171.