Àdùní Adé
Àdùní Adétí ó jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, àti módẹ́ẹ̀lì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Keje oṣù Kẹfà ọdún 1976.[1][2]
Àdùní Adé(Adéwálé) | |
---|---|
Adunni at the AMVCA 2020 | |
Ọjọ́ìbí | Àdùní Adéwálé 7 Oṣù Kẹfà 1976 Queens, New York, U.S.A. |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian American |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Kentucky |
Iṣẹ́ | Actress, Model |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Olólùfẹ́ | Nil |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Àdùní ní ìlú New York ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.[3] Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ìlú Irish láti orílẹ̀-èdèGermany nígbà tí bàbá rẹ̀ jẹ́ Yorùbá ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4] Wọ́n tọ́ Àdùní ní Ìpínlẹ̀ Èkó ati ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti Ìpínlẹ̀ Ògùn. Bàbá rẹ̀ fẹ́ràn aí kí ó kọ́ ìmọ̀ nípa ìṣirò owó ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Kentucky ní ọdún 2008.[5]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeAdùní ti ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ mádàámi-dófò kan ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ṣáájú kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ eré ṣíse. Ó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ módẹ́ẹ̀lì tí wọ́n gbé àsọ tuntun jáde. Ó kópa nínú ìdíje America's Next Top Model. Lẹ́yìn tí ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó kópa nínú eré àkọ́kọ́ rẹ̀ ní agbo Nollywood nínú eré Yorùbá kan tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní "You or I" ní ọdún 2013. Ó tún ti kópa nínú eré èdè Gẹ̀ẹ́sì àti ti Yorùbá. Ó ti kupa nínú fọ́ran àwo orin gbajú-gbajà olórin Sound Sultan àti Ice Prince kọ.[6][7]Àdùní ti gba amì-ẹ̀yẹ Stella Award ní ilé-iṣẹ́ Nigerian Institute of Journalism fún ipa rẹ̀ tí ó ń kó pélú bí ó ṣe ń gbé àṣà Yorùbá lárugẹ.[8] Ó di aṣojú fún ilé-iṣẹ́ OUD Majestic ní ọdún 2017.[9]
Ìgbé ayé rẹ̀
àtúnṣeÀdùní ti bímọ méjì tí orúkọ wọn ń jẹ́ D'Marion àti Ayden.[10] Àdùní fi léde nínú ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nuwò kan wípé òun kò ní fẹ́ ọkọ mìíràn mọ́ lẹ́yìn ẹni akọ́kọ́ tí òun ti bímọ fún tí àwọn sì ti pín yà. [11][12][13]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- Iwo tabi emi (You or I) (2013)[14][15]
- What's Within (2014)
- 2nd Honeymoon (2014)
- Head Gone (2015)
- So in Love. (2015)
- Schemers (2016)
- Diary of a Lagos Girl (2016)
- Diary of a Lagos girl (2016)
- For The Wrong Reasons (2016)
- It's Her Day (2016) Earned her the nomination for Best Supporting Actress in Africa's biggest Movie Awards, AMVCA in 2017. She also won Best Supporting Actress Award at the Lagos Film Festival for the movie.
- The Blogger's Wife (2017)
- Guyn Man (2017)
- Boss of All Bosses (2018)
- The Vendor (2018)
- House Of Contention (2019)
Àwọn eré orí amóhù-máwòrán
àtúnṣe- Behind the Cloud
- Babatunde Diaries
- Jenifa's Diary Season 2
- Sons of the caliphate Season 2
See also
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I am a sucker for Love". The Nation. http://thenationonlineng.net/im-a-sucker-for-love/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Nollywood actress reveals nationality says marriage is not in her agenda". Naija gists. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Adunni Ade … Chic, Sexy N' Expressive". The Guardian. Archived from the original on January 24, 2018. https://web.archive.org/web/20180124071204/https://guardian.ng/life/on-the-cover/adunni-ade-chic-sexy-n-expressive/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ Elizabeth Akindele. "Adunni Ade: Stylish diva". New Telegrah. Archived from the original on September 22, 2018. https://web.archive.org/web/20180922235840/https://newtelegraphonline.com/2017/12/adunni-ade-stylish-diva/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "ADUNNI ADE TALKS ON HER MIXED BACKGROUND & GROWING UP". Soundcity Television. Archived from the original on October 13, 2020. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "I was extremely nervous in my first movie – Adunni Ade, actress". Sun news. http://sunnewsonline.com/i-was-extremely-nervous-in-my-first-movie-adunni-ade-actress/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "'Why I debuted in Saidi Balogun's You and I'-Adunni Adewale". Encomium. http://encomium.ng/why-i-debuted-in-saidi-baloguns-you-and-i-adunni-adewale/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Adunni appreciates NIJ". The Nation. http://thenationonlineng.net/adunni-ade-appreciates-nij-students/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Adunni Ade and Bolanle Ninolowo Unveil The #OUDMAJSETICINSPIREMAGIC Ad Campaign For Oud Majestic Luxury Perfume Store".
- ↑ "Adunni Ade opens up about Life as a Single Parent, Overcoming Personal Obstacles, Finding Love & More in Latest Issue of Motherhood In-Style Magazine". BellaNaija. https://www.bellanaija.com/2017/04/adunni-ade-opens-up-about-life-as-a-single-parent-overcoming-personal-obstacles-finding-love-more-in-latest-issue-of-motherhood-in-style-magazine/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Checkout actress Aduni Ade and her adorable two sons". Nigeriafilms. https://www.nigeriafilms.com/movie-news/81-celebrity/42320-check-out-actress-adunni-ade-and-her-adorable-two-sons.
- ↑ "ADUNNI ADE APPRECIATES NIJ STUDENTS". The Nation. http://thenationonlineng.net/im-a-sucker-for-love/. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "Why I Did Not Marry The Father Of My Children- Adunni Ade". Naij. https://entertainment.naija.ng/577424-not-marry-father-children-nollywood-actress-speaks.html#577424. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "8 things you should know about Adunni Ade". The Pulse. http://www.pulse.ng/entertainment/movies/adunni-ade-8-things-you-should-know-about-actress-id5122254.html. Retrieved January 22, 2018.
- ↑ "I'm Proud Of My Yoruba Background – Actress, Adunni". Naij. Archived from the original on July 24, 2018. https://web.archive.org/web/20180724032510/https://www.naija.ng/57882.html. Retrieved January 22, 2018.