Àgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Abadam
(Àtúnjúwe láti Àgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀)
Abadam jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ Ìjọba ìbílẹ̀ Ìpínlẹ̀ Borno, Nàìjíríà, ní apá ìwọ oòrùn Lake Chad. Àwọn àlà rẹ̀ ni Chad àti Niger, ó sì sún mọ́ Cameroon, ní ọdún 2016, àwọn olùgbé rẹ̀ tó 140,000 [1] Olú ìlú rẹ̀ wà ní Malumfatori. Ètò àbò àti ìlera ara[2] wà lára àwọn ìdojúkọ ní agbẹ̀gbẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ Abadam. Abadam ní ilẹ̀ tí ó tó 3,973 km2
Abadam | |||
---|---|---|---|
Coordinates: 13°36′39″N 13°16′40″E / 13.610953°N 13.277664°ECoordinates: 13°36′39″N 13°16′40″E / 13.610953°N 13.277664°E | |||
Country | Nigeria | ||
State | Borno State | ||
Local Government Headquarter | Malumfatori | ||
Population (2006) | |||
• Total | 100,180 | ||
Time zone | UTC+1 (WAT) | ||
|
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ {{Cite web |title=Population – Borno State Government |url=https://bornostate.gov.ng/population/ |access-date=2022-10-07 |language=en-US}}
- ↑ "Have you been there? firsthand Information on Abadam Local Government in Borno State". Have you been there? firsthand Information on Abadam Local Government in Borno State. Retrieved 2022-10-07.