Àsìkò Ìwọòrùn Áfríkà

(Àtúnjúwe láti West Africa Time)

Àsìkò Ìwọòrùn Áfríkà tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pè ní West Africa Time tí ìkékúrú rẹ̀ jẹ́ WAT, [1]ni akókò tí a ń ló ní agbègbè àárín gbùngbùn Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé GMT) ni wọ́n ń ló ní orílẹ̀-èdè Benin tí òun náà wà ní inú ilẹ̀ Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀. WAT yí fi wákàtí kan léwájú UTC (+1) , èyí jẹ́ kí ó ṣe déédé pẹ̀lú Central European Time. Púpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí wọ́n ń ṣamúlò UTC ni akókò an ma ń jẹ́ (UTC +0) .[2]

Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń lo UTCÀtúnṣe

(western)ItokasiÀtúnṣe

  1. "Time in West Africa". GMT - World Time & Converters. Retrieved 2022-10-20. 
  2. "WAT". WorldTimeServer.com. 2016-01-08. Retrieved 2022-10-20.