Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò
(Àtúnjúwe láti Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Congo)
Wọ́n kéde àrùn COVID-19 àkọ́kọ́ ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò lọ́jọ́ lóṣù kẹta ọdún 2020.
Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Congo | |
---|---|
Àrùn | COVID-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Republic of the Congo |
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́ | Wuhan, China |
Index case | Brazzaville |
Arrival date | 14 March 2020 (4 years, 8 months and 3 days) |
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 1,087 (as of 25 June)[1] |
Active cases | 594 (as of 25 June) |
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 456 (as of 25 June) |
Iye àwọn aláìsí | 37 (as of 25 June) |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeLọ́jọ́ Kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà, Covid-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ WHO lọ́jọ́ kokànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019.[2][3]
Iye ìjàm̀bá ikú àrùn Covid-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severe acute respiratory syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 2003,[4][5] ṣùgbọ́n jíjàkálẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lọ iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀.[6][4]
Ẹ yẹ̀yí wò
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "MINISTERE DE LA SANTE, DE LA POPULATION, DE LA PROMOTION DE LA FEMME ET DE L'INTEGRATION DE LA FEMME AU DEVELOPPEMENT". www.sante.gouv.cg. Retrieved 2020-06-25.
- ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)