Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ímò
Ìpínlẹ̀ Imo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1976, àwọn Àtòjọ àwọn Gómìnà Gómìnà tí wọ́n ti ja ní Ìpínlẹ̀ naa:
Orúkọ | Ipò tí wọ́n dì mú | Ìgbà tí wọ́n gbàjọba | Àsìkò tí wọ́n kúrò nípò | Ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú wọn | Notes |
---|---|---|---|---|---|
Ndubuisi Kanu | Governor | Mar 1976 | 1977 | (Military) | |
Adekunle Lawal | Governor | 1977 | Jul 1978 | (Military) | |
Sunday Ajibade Adenihun | Governor | Jul 1978 | Oct 1979 | (Military) | |
Samuel Onunaka Mbakwe | Governor | 1 Oct 1979 | 31 Dec 1983 | NPN | |
Ike Nwachukwu | Governor | Jan 1984 | Aug 1985 | (Military) | |
Allison Amakoduna Madueke | Governor | Aug 1985 | 1986 | (Military) | |
Amadi Ikwechegh | Governor | 1986 | 1990 | (Military) | |
Anthony E. Oguguo | Governor | Aug 1990 | Jan 1992 | (Military) | |
Evan Enwerem | Governor | Jan 1992 | Nov 1993 | NRC | |
James N.J. Aneke | Administrator | 9 Dec 1993 | 22 Aug 1996 | (Military) | |
Tanko Zubairu | Administrator | 22 Aug 1996 | May 1999 | (Military) | |
Achike Udenwa | Governor | 29 May 1999 | 29 May 2007 | PDP | |
Ikedi G. Ohakim | Governor | 29 May 2007 | 2011 | PPA / PDP | |
Owelle Rochas Anayo Okorocha | Governor | 2011 | 2019 | PPA / PDP | |
Emeka Ihedioha | Governor | 2019 | 2020 | PPA / PDP | |
Hope Uzodinma | Governor | 2020 | PPA / PDP |
Ẹ tún lè wo
àtúnṣeÀwọn ìtókasí
àtúnṣe- "Nigerian Federal States". WorldStatesmen. Retrieved 2009-11-30.