Àkójọ (físíksì)
Àkójọ jẹ́ ohun ìní kan tí àwọn akórajọ àfojúrí ní. Àkójọ jẹ́ iyeọ̀pọ̀ èlò tó wà nínú akórajọ kan. Nínú sístẹ́mù ẹyọ ìwọ̀n SI, àkójọ únjẹ́ wíwọ̀n ní kìlógrámù, ó ṣì jẹ́ ẹyọ ìwọ̀n ìpìlẹ̀ nínú sístẹ́mù yìí.
Fún àpẹrẹ àkójọ Ayé jẹ́ 5,98 × 1024 kg.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |