Ayé, tàbí Ilé-ayé jẹ́ pálánẹ́ẹ̀tì kẹta ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ láti ọ̀dọ ọ̀run, ó sì jẹ́ èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn pálánẹ́ẹ̀tì tí wọ́n ní ilẹ̀ tí ó ṣe é tẹ̀. 🜨

Ayé  🜨
"The Blue Marble" photograph of Earth,
taken from Apollo 17
Ìfúnlọ́rúkọ
Ìpolongo Gbígbọ́i /ˈa/
Alápèjúwe earthly, tellurian, telluric, terran, terrestrial.
Àsìkò J2000.0[note 1]
Aphelion152,098,232 km
1.01671388 AU[note 2]
Perihelion 147,098,290 km
0.98329134 AU[note 2]
Semi-major axis 149,598,261 km
1.00000261 AU[1]
Eccentricity 0.01671123[1]
Àsìkò ìgbàyípo 365.256363004 days[2]
1.000017421 yr
Average orbital speed 29.78 km/s[3]
107,200 km/h
Mean anomaly 357.51716°[3]
Inclination 7.155° to Sun's equator
1.57869°[4] to invariable plane
Longitude of ascending node 348.73936°[3][note 3]
Argument of perihelion 114.20783°[3][note 4]
Satellites 1 (the Òṣùpá)
Àwọn ìhùwà àdánidá
Iyeìdáméjì ìfẹ̀kiri 6,371.0 km[5]
Ìfẹ̀kiri alágedeméjì 6,378.1 km[6]
Ìfẹ̀kiri olóòpó 6,356.8 km[7]
Flattening 0.0033528[6]
Circumference 40,075.16 km (equatorial)[8]
40,008.00 km (meridional)[8]
Ààlà ojúde 510,072,000 km2[9][10][note 5]

148,940,000 km2 land (29.2 %)

361,132,000 km2 water (70.8 %)
Ìpọ̀sí 1.08321 × 1012 km3[3]
Àkójọ 5.9736 × 1024 kg[3]
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ 5.515 g/cm3[3]
Equatorial surface gravity9.780327 m/s2[11]
0.99732 g
Escape velocity11.186 km/s[3]
Sidereal rotation
period
0.99726968 d[12]
23h 56m 4.100s
Equatorial rotation velocity 1,674.4 km/h (465.1 m/s)[13]
Axial tilt 23°26'21".4119[2]
Albedo0.367 (geometric)[3]
0.306 (Bond)[3]
Ìgbónásí ojúde
   Kelvin
   Celsius
minmeanmax
184 K[14]287.2 K[15]331 K[16]
-89.2 °C14 °C57.8 °C
Afẹ́fẹ́àyíká
Ìfúnpá ojúde 101.325 kPa (MSL)
Ìkósínú 78.08% nitrogen (N2)[3]
20.95% oxygen (O2)
0.93% argon
0.038% carbon dioxide
About 1% water vapor (varies with climate)

Ilé-ayé jé pálánẹ́ẹ̀tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní òde ojú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ sìni Ilé-ayé nìkan ni pálánẹ́ẹ̀tì tí a mọ̀ ní àgbáńlá ayé. Ojú-òrun (atmosphere) jẹ́ kìkì nitrogen àti oxygen tí ó ń dà àbò bo ilé-ayé lọ́wọ́ àtaǹgbóná (radiation) tó léwu sí ènìyàn. Bákan náà ojú-òrun kò gba àwọn yanrìn-òrun láàyè láti jábọ́ sí ilé-ayé nípa sísun wọ́n níná kí wọ́n ó tó lè jábọ́ sí ilé-ayé. [7]

Òṣùpá ati Ilé-ayé

Àwọn Ìtókasí àtúnṣe

 1. 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named standish_williams_iau
 2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named IERS
 3. 3.00 3.01 3.02 3.03 3.04 3.05 3.06 3.07 3.08 3.09 3.10 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named earth_fact_sheet
 4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Allen294
 5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named hbcp2000
 6. 6.0 6.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named iers
 7. 7.0 7.1 Cazenave, Anny (1995). "Geoid, Topography and Distribution of Landforms". In Ahrens, Thomas J (PDF). Global earth physics a handbook of physical constants. Washington, DC: American Geophysical Union. ISBN 0-87590-851-9. Archived from the original on 2006-10-16. https://web.archive.org/web/20061016024803/http://www.agu.org/reference/gephys/5_cazenave.pdf. Retrieved 2008-08-03. 
 8. 8.0 8.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named rosenbout
 9. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Pidwirny 2006
 10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named cia
 11. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named yoder12
 12. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Allen296
 13. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Cox2000
 14. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named asu_lowest_temp
 15. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named kinver20091210
 16. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named asu_highest_temp


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found