Ede Wolof jẹ èdè tí à ń sọ ni atí bèbè Senegal Mílíọ̀nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ. Awọn Olùbágbè wọn ni Mandika ati Fulaní. Awọn isẹ́ ọna wọn màa ń rewà tó sì ma ń ní àmìn àti àwòràn àwọn asáájú nínú ẹ̀sìn musulumi. Ìtan Wolof ti wà láti bí ẹgbẹ̀rún ọdún méjìlá tàbí métàlá sẹ́yìn. Ìtàn ẹbí alátẹnudẹ́nu wọn sọ pé ọ̀kan lára àwọn tó kọkọ tẹ̀dó síbí yìí jẹ́ awọn to wa láti orífun Fulbe. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwọn orin oríkì èyí ti a ma ń gbọ́ láti ẹnu àwọn ‘Griots’ àwọn akéwì. Mùsùlùmí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọnm ará Wolof.

Wolof
Sísọ ní Sẹ̀nẹ̀gàl

 Gámbíà

 Mauritáníà
AgbègbèWest Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀3.2 million (mother tongue)
3.5 million (second language) [1]
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ níKòsí
Àkóso lọ́wọ́CLAD (Centre de linguistique appliquée de Dakar)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1wo
ISO 639-2wol
ISO 639-3either:
wol – Wolof
wof – Gambian Wolof
Èdè Wolof


  1. Gordon, Raymond G., Jr. (ed.), 2005. Ethnologue: Languages of the World, Fifteenth edition. Dallas, Tex.: SIL International. Online version: http://www.ethnologue.com/, wolof entry here