Èdè Efe

(Àtúnjúwe láti Èdè efe)

Èdè Efe tabi èdè Ewe (tabi efegbe) je ede Niger-Kongo ti won n lo ni Ghana, Togo ati Benin.

Ewe
Eʋe, Eʋegbe
Sísọ níGhana, Togo
AgbègbèSouthern Ghana east of the Volta River, southern Togo
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀over 3 million, with 500,000 second language speakers
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1ee
ISO 639-2ewe
ISO 639-3ewe

Èdè olóhùn ní èdè yìí orísìí àmì òhun merin ni wọn ń fi ń pe e. Ni abe Ẹbi Niger Congo ni èdè yìí wa.

Mílíọ̀nù mẹta ni iye àwọn tí ń sọ èdè yìí. (3 Million).