Ìbálòpọ̀ tàbí Iyàrá ẹni lòpọ̀) Jẹ́ gbólóhùn kan tí ó ń tọ́ka sí ìdàpọ̀, ìwọ̀nú-bọ̀nú akọ àti abo (ọkùnrin àti obìnrin), nípa kí akọ ó ki nkan ọmọkùnrin rẹ̀ bọ inú ojú nkan ọmọbìrin abo yálà léte àti ṣòwò ọmọ ni tàbí fi ṣeré lákọ-lábo tàbí méjèèjì[1] A tún mo eléyí sí vaginal intercourse or vaginal sex.[2][3]

Sexual intercourse in the missionary position depicted by Édouard-Henri Avril (1892)

Àwọn ọ̀nà ìbálòpọ̀

àtúnṣe

Lára àwọn ọ̀nà míràn tí ènìyàn lè gbà ní àṣepọ́ ni:

  1. kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ láti fùrọ̀ tí ó túmọ̀ sí wípé àkọ tàbí ọkùnrin yòó ki nkan ọmọkùnrin rẹ̀ bọ ojú ilé-ìgbẹ́ abo láti ba ní àṣepọ̀.
  2. kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ láti ẹnu, èyí túmọ̀ sí wípé àkọ tàbí ọkùnrin yòó ki nkan ọmọkùnrin rẹ̀ bọ ẹnu olólùfẹ́ rẹ̀ láti ní àṣepọ̀.
  3. kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ nípa fífi ìka ro abẹ́ obìnrin.
  4. kí wọ́n ní ìbálòpọ̀ nípa lílo àwọn ohun èlò ìbálòpọ̀ tí wọ́n gbẹ́ bí nkan ọmọkùnrin.

Àmọ́ irúfẹ́ àwọn ọ̀nà ìbálòpọ̀ tí a kà sílẹ̀ yí kò bá ìlànà àṣà Yorùbá mu yàtọ̀ sí kí á bára ẹni lò pọ̀ láti ojú ara, èyí tí ó tọ̀nà jùlọ.[4][5][6]

Sexual intercourse between a man and a woman

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Sexual intercourse most commonly means penile–vaginal penetration for sexual pleasure and/or sexual reproduction; dictionary sources state that it especially means this, and scholarly sources over the years agree. See, for example;
  2. Essential Concepts for Healthy Living. Jones & Bartlett Publishers. 2012. pp. 180–181. ISBN 978-1449630621. https://books.google.com/books?id=VegUiVbruBMC&pg=PA180. "Most heterosexuals are familiar with the notion of 'having sex' or sexual intercourse as vaginal sex, the insertion of a penis into a vagina. Vaginal sex, or coitus, is the most common and popular form of intimate sexual activity between partners." 
  3. Sexuality Now: Embracing Diversity. Cengage Learning. 2018. p. 289. ISBN 978-1337672061. https://books.google.com/books?id=9A9EDwAAQBAJ&pg=PT289. "Vaginal intercourse (also referred to as sexual intercourse) involves inserting the penis into the vagina." 
  4. "Sexual Intercourse". Discovery.com. Archived from the original on August 22, 2008. Retrieved January 12, 2008. 
  5. Rathus, S.A.; Nevid, J.S.; Fichner-Rathus, L. (2011). Human Sexuality in a World of Diversity. Human Sexuality in a World of Diversity. Allyn & Bacon. ISBN 978-0-205-82175-4. https://books.google.com/books?id=ZotYAAAAYAAJ. Retrieved 2022-03-08. 
  6. Freberg, L. (2009). Discovering Biological Psychology. Cengage Learning. p. 308. ISBN 978-0-547-17779-3. https://books.google.com/books?id=-zyTMXAjzQsC&pg=PA308. Retrieved 2022-03-08.