Ìfètò sọ́mọ bíbí
Ìfètò sọ́mọ bíbí ni a lè pe ní ìlànà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí ó ní ṣe pẹ̀lú bí a ṣe lè pinu lórí iye ọmọ tí ó bá wuni láti bí, láì kò sí ìjẹni nípa lórí bí a ṣe lè fi àsìkò sí àárín àwọn ọmọ tí a fẹ́ bí náà lọ́nà tí kò ní pa wá lára, yálà ní Oògùn lílò, ìgbé ayé tí ó dára nínú àwùjọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ni àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .[1] Ètò ìlànà ìfètò sọ́ọ́mọ bíbí tún dá lórí pípinu lórí bóyá kí obìnrin ó me iye ọmọ tí ó bá fẹ́ bí kí ó sì fi àsìkò sí àárín wọn, tàbí kí ó pinu lá má tilẹ̀ dábàá àti bímọ kankan rárá láyé rẹ̀, tàbí kí ó fi aye sílẹ̀ fún ọmọ bíbí nínú ònkà ọjọ́ ayé rẹ̀ tí ó fẹ́ fi bímọ. Àwọn ìpinu tí a ká sókè yí ni àyípadà ma ń dé bá látàrí àwọn kókó bí :
- àìlówó lọ́wọ́
- uṣẹ́ òòjọ́ obìnrin (career),
- ipo Ìgbéyàwó
- àwọn kùdìẹ̀-kudiẹ tí ó lè mú kí lọ́kọ-láyà ó má lè rọ́mọ bí nínú Ìgbéyàwó wọn, tàbí kí wọ́n má lè tọ́ àwọn ọmọ tí wọ́n bá bí.
Àwọn Ìlànà ìfètò sọ́mọ bíbí
àtúnṣeTí lọ́kọ-láyà bá sì wà nípò àti bímọ, tí wọ́n sì ti ní àwọn ọmọ nílẹ̀ rẹpẹtẹ, àmọ́ ayé sì tún wà láti bímọ si, ayé wà fún wọn láti lo oògùn tí wọ́n lè fi fètò sọ́mọ bíbí wọn, tàbí kí wọ́n lo àwọn ọ̀nà mìíràn láti fi fètò sọ́mọ bíbí wọn pẹ̀lú.[2][3] Àwọn ìlànà míràn ni ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbálòpọ̀ [3][1], Ìdáàbòbò àbójútó àwọn àrùn ìbálòpọ̀ ọlọ́kan ò jọ̀kan.[3] ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ṣáájú kí obìnrin tó lóyún,àti àbójútó Oyún.
Àṣìgbọ́ ọ̀rọ̀ nípa ìfètò sọ́mọ bíbí
àtúnṣeOyún ṣíṣẹ́ kìí ṣe dandan la lára ìlànà ìfètò sọ́mọ bíbí, lóòtọ́, oògùn lílò àti àwọn ìlànà míràn ti a ti la kalẹ̀ ma ń dènà kí obìnrin ṣẹ́yún. Family planning, as defined by the United Nations and the World Health Organization, encompasses services leading up to conception. Abortion is not considered a component of family planning,[4] [5] Pupọ̀ nínú àwọn obìnrin tí wọ́n ń lo oògùn láti fi de na oyún ni wọ́n ń ṣe ìfètò sọ́mọ bíbí. Àwọn bí wúndíá, ọ̀dọ́mọ bìnrin tí kò tíì lọ́kọ, àwọn lọ́kọ-láyà tí wọ́n fẹ́ ṣiṣẹ́ lówó lọ́eọ́ kí wọ́n tó bímọ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "National Child Abuse and Neglect Data System Glossary" (PDF). Administration for Children & Families. 2000. Archived from the original (PDF) on 20 October 2020. Retrieved 30 October 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWHOFP
- ↑ 3.0 3.1 3.2 "What services do family planning clinics provide?". NHS. Archived from the original on 11 November 2014. Retrieved 8 March 2008. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ United Nations Population Fund. "Family planning" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 March 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Bajos, N.; Le Guen, M.; Bohet, A.; Panjo, Henri; Moreau, C. (2014). "Effectiveness of family planning policies: The abortion paradox". PLOS ONE 9 (3): e91539. doi:10.1371/journal.pone.0091539. PMC 3966771. PMID 24670784. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3966771.