Ìgbà Kámbríà (Cambrian) ni igba oniseorooriile akoko ti Àsíkò Ìgbéàtijọ́, to pari lati 542 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn dé 488.3 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn (ICS, 2004,[5] chart); Ìgbà Ọ̀rdòfísíà ni o tele. Ko si ojutu bo se pin si. Adam Sedgwick lo sedasile igba yi, o pe ni Cambria, oruko ede Latin fun Wales, nibi ti awon apata Britani Igba Kambria ti yojade daada.[6]

Ìgbà Kámbríà
Ìgbà Kámbríà
542–488.3 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdun sẹ́yìn
Mean atmospheric O2 content over period duration ca. 12.5 Vol %[1]
(63 % of modern level)
Mean atmospheric CO2 content over period duration ca. 4500 ppm[2]
(16 times pre-industrial level)
Mean surface temperature over period duration ca. 21 °C[3]
(7 °C above modern level)
Sea level (above present day) Rising steadily from 30m to 90m[4]


  1. Image:Sauerstoffgehalt-1000mj.svg
  2. Image:Phanerozoic Carbon Dioxide.png
  3. Image:All palaeotemps.png
  4. Haq, B. U.; Schutter, SR (2008). "A Chronology of Paleozoic Sea-Level Changes". Science 322 (5898): 64. doi:10.1126/science.1161648. PMID 18832639. 
  5. Gradstein, Felix M.; Ogg, J. G.; Smith, A. G. (2004). A Geologic Time Scale 2004. Cambridge: Cambridge University Press. ISBN 0521786738. 
  6. Sedgwick, A. (1852). "On the classification and nomenclature of the Lower Paleozoic rocks of England and Wales". Q. J. Geol. Soc. Land. 8: 136–138. doi:10.1144/GSL.JGS.1852.008.01-02.20. 
Preceded by Proterozoic Eon 542 Ma - Phanerozoic Eon - Present
542 Ma - Paleozoic Era - 251 Ma 251 Ma - Mesozoic Era - 65 Ma 65 Ma - Cenozoic Era - Present
Kámbríà Ọ̀rdòfísíà Sílúríà Dẹfoníà Eléèédú Pẹ́rmíà Tríásíkì Jùrásíkì Ẹlẹ́fun Ìbíniàtijọ́ Ìbíniọ̀tun Quaternary