Ìgbéríko Àrin (Kẹ́nyà)
Ìgbéríko Àrin Kenya ni agbegbe 'keta to o kere ju lo ni Orile Ede Kenya, lehin agbegbe Nairobi, ati agbegbe Iwo Oorun, pelu Àpapọ̀ iye ààlà 13,191 km2 (5,093.1 sq m).agegbe naa wa ni iha Ariwa si ilu Nairobi, ati iha Iwo O'orun si oke Kenya. Ni Ikaniyan to odun 2009, agbegbe naa ni iye eniyan Olùgbé 4,383,743. Olu ilu agbegbe naa ni ilu Nyeri.Agbegbe aarin Kenya je Ile isenbaye ti awon eya Kikuyu.
Ìgbéríko Àrin | |
---|---|
Location in Kenya. | |
Country | Kenya |
No. of districts: | 12 |
Capital | Nyeri |
Area | |
• Total | 13,191 km2 (5,093 sq mi) |
Population (2007) | |
• Total | 4,145,000 |
Time zone | UTC+3 (EAT) |
Kilimati
àtúnṣekilimati Agbegbe aarin Kenya ni akoto tutu ju awon agbegbe iyoku orile Ede naa lo, nitori wipe, agbegbe naa wa no ile giga ju awon agbegbe 'yoku lo.Ojo maa n ro ni asiko meji ninu Odun. L'akoko lati osu Iketa(March), so osu karun-un(May), ati asiko elekeji to o bere ni Osu Kewaa(october} ati osu Ikakanla(November). Awon ojo akoko elekeji wonyii ni a mo si awon ojo asiko kukuru
Imo akoto
àtúnṣeÀyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |