Ìjọba ìbílẹ̀ Obòkun
'Obòkun jẹ́ Ìjọba Ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ilé ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀ wà ní Ibòkun at7°47′00″N 4°43′00″E / 7.78333°N 4.71667°E.
Obòkun | |
---|---|
Coordinates: 7°47′N 4°46′E / 7.783°N 4.767°ECoordinates: 7°47′N 4°46′E / 7.783°N 4.767°E | |
Nàìjíríà | Nigeria |
State | Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun |
Government | |
• Alága ìjọba Ìbílẹ̀ | Chief Mrs Olatunde Adejoke |
Area | |
• Total | 527 km2 (203 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 116,511 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 233 |
ISO 3166 code | NG.OS.OB |
Ìjọba ìbílẹ̀ Obòkun ní ilé tí ó tó 527 km2 tí àwọn olùgbé ibẹ̀ lápapọ̀ sì tó 116,511 níye gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ṣe fi lélẹ̀.
Nọ́mbà ìlà ìpè tí ó ja sí agbègbè naa ni 233.[1] Lára àwọn ìlú tí wọ́n mú lè ti Obòkun ni Ìmẹ̀sí- Ilé, Ọ̀tàn-Ilé Ẹ̀sà-Òkè, Ẹ̀sà-Odo, Ìlànàẹ̀, Ìpọ́ndà, Ìkíyinwá, Ọrà àti Ìdómìnàsì.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on November 26, 2012. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "List of Towns and Villages in ibokun L.G.A". Nigeria Zip Codes. 2014-03-03. Retrieved 2021-01-10.