Ìròyìn Oṣù Kínní 2011
Osu Kinni
àtúnṣe- Laurent Gbagbo ati Alassane Ouattara pe ara wọn ní Ààrẹ ilẹ̀ Côte d'Ivoire lẹ́yìn àríyànjiyàn lórí èsì ìdìbòyàn ààrẹ 2010
- Ọlọ́ọ̀pá Nàìjíríà fẹ̀sùn kan Alàgbà Teslim Folarin àti àwọn mẹ́tà míràn pé wọn lọ́wọ́ nínú ikú Lateef Salako a.k.a Eleweomo ní Ibadan.
- Kòlómbìà, Jẹ́mánì, Índíà, Pọ́rtúgàl, àti Gúúsù Áfríkà bẹ̀rẹ̀ ìgbà ọdún mẹ́jì bíi ọmọẹgbẹ́ aláìjẹ́ déédé Ìgbìmọ̀ Àbò Àgbájọ Aparapọ̀ àwọn Orílẹ̀-èdè.