Ẹ̀kọ
Agidi tabi Eko jẹ ounjẹ Naijiria ti a ṣe pẹlu iyẹfun oka.
(Àtúnjúwe láti Ògì)
Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà, tí wón sì ń fi àgbàdo, ọkà tàbí jéró ṣe.[1][2][3][4] Bí wọ́n bá fẹ́ se ògì, wọ́n á rẹ àgbàdo,, ọkà tàbí jéró sínú omi fún ọjọ́ méjì sí mẹta kí wón tó lọ̀ ọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n ọ́ fi kalẹ̀ fún bí í ọjọ́ mẹ́ta mìíràn láti kan, lẹ́yìn èyí, wọ́n le sè é. Wọ́n máa ń fi àkàrà, mọ́ín mọ́ín àti àwọn oúnjẹ míràn mu ẹ̀kọ.
Alternative names | Akamu, eko |
---|---|
Type | Pap tàbí pudding |
Place of origin | Nàìjíríà, Kenya, Cameroon |
Region or state | ìwọ̀ oòrùn Africa |
Main ingredients | àgbàdo, ọkà tàbí jéró |
Ingredients generally used | sugar |
Variations | Uji ní Kenya |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Àwon Ìtókasí
àtúnṣeÀyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Fermented Cereals - A Global Perspective". United Nations FAO. Retrieved 2006-07-22.
- ↑ "Process of making Ogi (pap, akamu)". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-26. Retrieved 2022-06-01.
- ↑ Kenzap (2020-07-14). "AKAMU/OGI (PAP)". Diet Tech Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-01.
- ↑ "Oloye Corn Meal - Akamu / Pap / Koko/ogi". My Sasun (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-01.