Òkun Kàríbẹ́ánì

Okun Karibeani je omi okun ti Okun Atlantiki ni ibioloru ni Western hemisphere. O ni ala ni guusuiwoorun mo awon orile-ede Arin Amerika ti Panama, si iwoorun mo Costa Rica, Nicaragua, Honduras, Guatemala, Belize, ati Mexico, si ariwa mo The Greater Antilles (Cuba, Jamaica, Hispaniola, ati Puerto Rico), ati si ilaorun mo the Lesser Antilles.[1]

The Caribbean Sea


ItokasiÀtúnṣe

  1. The Caribbean Sea World Wildlife Fund. Website last accessed 5 December 2008