Ẹ̀bùnolúwa
Orúkọ Yorùbá tí ó túmọ̀ sí Ẹ̀bùn Ọlọrún.
Ẹ̀bùnolúwa audio (ìrànwọ́·ìkéde) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ma ń fún ọmọ ọkùnrin tàbí obìnrin látinú Yorùbá tó túmọ̀ sí "Ẹ̀bùn Ọlọ́run”.[1][2][3] Àwọn ìgékúrú orúkọ náà ni Ẹ̀bùn, Ẹ̀bùnolú.
ẹ̀yà | Takọ, tabo | ||
---|---|---|---|
Èdè | Yorùbá | ||
Ìpìlẹ̀ṣẹ̀ | Ọ̀rọ̀ / orúkọ | Nàìjíríà | |
Ìtumọ̀ | Ẹ̀bùn Ọlọ́run | ||
Orísun | South-West Nigeria | ||
Àwọn orúkọ mìíràn | |||
Fọ́ọ̀mù kúkúrú | Ebun |
Orúkọ yìí ní àkànpọ̀ méjì: “Ẹ̀bùn” tó túmọ̀ sí “gift” ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti “Olúwa” tó túmọ̀ sí “God” ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ìtumọ̀ rẹ̀ ń tọ́kasí iyì àti ìbùkún tí a fi sínú ẹnikẹ́ni tí ó ń jẹ́ orúkọ yìí, ní ọ̀pọ̀ ìgbà ń ṣe àfihàn àwọn ìrètí gíga àti ìmọ̀rírí ẹ̀mí àwọn òbí. [4]
Àwọn ènìyàn olókìkí tí ó ń jẹ́ orúkọ náà
àtúnṣe- Burna Boy (Damini Ebunoluwa Ogulu), olórin Nàìjíríà
- Mobolanle Ebunoluwa Sotunsa, Nigerian Academic
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ẹ̀bùnolúwa". www.yorubaname.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-05.
- ↑ "Ebunoluwa Name Meaning, Origin, Numerology & Popularity - Drlogy". drlogy.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2024-10-07. Retrieved 2024-10-07.
- ↑ Understanding Yoruba Life and Culture. Africa World Press. ISBN 9781592210251.
- ↑ "The meaning and history of the name Ebunoluwa". Venere. 2024-07-03. Retrieved 2024-10-14.