Abinuwaye
Ẹkáàbọ̀!
Ẹpẹ̀lẹ́ o, Abinuwaye,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 19:18, 27 Oṣù Kejì 2022 (UTC)
Àkíyèsí pàtàkì
àtúnṣeẸ káre Oníṣe:Abinuwaye, a dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún akitiyan yín lórí àwọn àfikún yín tí ẹ ń ṣe lórí iṣẹ́ àkànṣe WP Yorùbá, a dúpẹ́ púpọ̀. Àmọ́, a fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì kan wípé ẹní láti ṣe ògbufọ̀ gbogbo àyọkà sí èdè Yorùbá kúrò ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ó ṣe pàtàkì láti yí gbogbo rẹ̀ dà sí èdè Yorùbá, pàá pàá jùlọ àyọkà Who's the boss. Ẹ ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 18:28, 13 Oṣù Kẹta 2022 (UTC)