Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Idowuogbo,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 16:44, 15 Oṣù Kẹjọ 2021 (UTC)

E seun lópò-lopò fún ìgbaniwolé síhìn ín. Á seése ò! Idowuogbo (ọ̀rọ̀) 17:29, 15 Oṣù Kẹjọ 2021 (UTC)

Thank you Idowuogbo for creating Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-Osi on this Wiki. Agbalagba (ọ̀rọ̀)