Kenogenic
Ẹkáàbọ̀!
Ẹpẹ̀lẹ́ o, Kenogenic,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 16:07, 15 Oṣù Kọkànlá 2019 (UTC)
Eṣeun pupọ fun atilẹyin yin ejo moti ko ise miran lórí Paul Adefarasin ẹ jọ̀wọ́ eba mi gbe jade ko di òun ti gbogbo ẹ̀yán le ka
- Mo ti ṣeé Paul Adefarasin. T CellsTalk 08:26, 16 Oṣù Kejìlá 2019 (UTC)
Eṣeun pupọ mo dupẹ
Article and diacritical mark
àtúnṣeHello Kenogenic,
Thanks for your contributions to Yoruba Wikipedia, the community appreciate your help. However, it does appears you are not a native speaker of Yoruba language and you tend to create articles without the Yoruba diacritical marks ( mostly with what appears to be a Google translator). We do however want all articles to have diacritical marks and as such I'd ask you to not create new articles without diacritical marks as clean up of articles without diacritical marks consume too much of our volunteers time. You can work on maintenance pending when you learn and understand Yoruba orthography and diacritical marks. Please let me know if you have any question. Regards. T CellsTalk 06:40, 31 Oṣù Kejìlá 2019 (UTC)