Àkíyèsí àti ìkìlọ̀

àtúnṣe

Oní́ṣẹ́ Mbah Victor Chukwuemerie, a kí ọ káàbọ̀ sí àwùjọ àwọn aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá. A fẹ́ pe àkíyèsí rẹ sí àwọn àyọkà tí o ti dá sílẹ̀ sí orí Wiki yí wípé wọn kò bójú mu, bákan náà ni wọn kò bá ìlànà agbékalẹ̀ èdè Yorùbá mu pẹ̀lú. A sì tún ri wípé àwọn àyọkà rẹ pátá ni o fi irinṣé òùngbífọ̀ ṣe láì túnkọ pẹ̀lú èdè Yorùbá tó mọ́yánlórí, èyí túmọ̀ sí wípé ẹ kò gbọ́ èdè Yorùbá, ẹ kò sì mọ̀ọ́ kọ́ pẹ̀lú. Lílo irinṣẹ́ òngbífọ̀ yí ló lòdi ̀sí òfin àti ìlànà Yorùbá Wikipédíà. fúndí èyí, mo ma gbà ọ́ níyànjú kí o má ṣe dá àyọkà míràn sílẹ̀ mọ́ sórí wíkì yí mọ́. Bí o bá ní àríwísí kan, yára kàn sími níbí. O Seun.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 15:22, 28 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply

Mo ti dá ọ lẹ́kun

àtúnṣe

Oníṣẹ́@Mbah Victor Chukwuemerie, mo ti dá ọ lẹ́kun láti m dá àwọn àyọkà tuntun sórí wíkí yìí lẹ́yìn tí o lò gbọ́ ìkìlọ̀ àti àkiyesi pataki miAgbalagba (ọ̀rọ̀) Agbalagba (ọ̀rọ̀) 19:41, 28 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply

Appeal to revoke block please Mbah Victor Chukwuemerie (ọ̀rọ̀) 23:19, 28 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply
I will certainly abide to the rules from now onwards Mbah Victor Chukwuemerie (ọ̀rọ̀) 23:20, 28 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply
How do you plan to "abide to the rules onwards"? Thank you. T CellsTalk 11:41, 30 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply
I've come to to realize that contributing to the Yoruba Wikimedia requires learning and being trained on how to contribute on the Wikimedia Space.
My learning process will include being patient enough to learn and be mentored by experienced Wikimedians which would ensure I contribute meaningfully.
Also, I'm willing to sign up as your mentee so as to master the intricacies of being a good contributor to the Wikimedia projects. Mbah Victor Chukwuemerie (ọ̀rọ̀) 19:54, 30 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply
I have gone ahead to unblock you. Please be more careful in the future. T CellsTalk 21:05, 31 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024 (UTC)Reply
Thank you very much sir .
Please sir how can I reach out to you through calls or WhatsApp Mbah Victor Chukwuemerie (ọ̀rọ̀) 07:30, 3 Oṣù Òkúdu 2024 (UTC)Reply
Email me via reachout2isaac@gmail.com. Regards. T CellsTalk 08:17, 5 Oṣù Òkúdu 2024 (UTC)Reply
Ok sir Mbah Victor Chukwuemerie (ọ̀rọ̀) 20:04, 7 Oṣù Agẹmọ 2024 (UTC)Reply