Omosalewa Omiade
Joined 5 Oṣù Òwéwe 2021
Kú àbọ̀, kú iṣẹ́ takun takun
àtúnṣeẸkáàbọ̀!
Ẹpẹ̀lẹ́ o, Omosalewa Omiade,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! Agbalagba (ọ̀rọ̀) 10:25, 6 Oṣù Kẹ̀sán 2021 (UTC)