Omosalewa Omiade
Joined 5 Oṣù Òwéwe 2021
Orúkọ mi ni Omidan Ọmọ́ṣaléwá. Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá tó nífẹ̀ẹ́ sí àṣà, ìṣe àti èdè Yorùbá. Ìgbélárugẹ, ìdàgbàsókè àti ìsọlọ́jọ èdè àwọn ohun àjogúnbá Yorùbá ló jẹ mi lógún.