Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Tbiw,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀!

UntitledÀtúnṣe

Hello. I see your translations mostly are not proper Yoruba. Do you speak Yoruba? Demmy (ọ̀rọ̀) 13:47, 25 Oṣù Keje 2020 (UTC)

Explain more what you mean.Tbiw (ọ̀rọ̀) 13:49, 25 Oṣù Keje 2020 (UTC)
Most of your edits are bad translations into Yoruba. Not to discourage you just want to know if you need help? Demmy (ọ̀rọ̀) 14:25, 25 Oṣù Keje 2020 (UTC)
Okay. Help me maybe anytime i want start a new article i will tell you.Thanks buyo.Tbiw (ọ̀rọ̀) 15:14, 25 Oṣù Keje 2020 (UTC)
Tbiw, please what exactly do you want to know? I am ready to assit in a little way I can and in areas where I cannot, I will refer you to those who know more than me Sowoletoyin (ọ̀rọ̀) 12:56, 26 Oṣù Keje 2020 (UTC)
Thanks for accommodating me sowoletoyin i want to learn how to translate from English to Yoruba.Tbiw (ọ̀rọ̀) 06:01, 27 Oṣù Keje 2020 (UTC)

WikiVersity Yoruba ProjectÀtúnṣe

Mo dupe fun kikamiye ti e ka mi ye lati kopa ninu WikiVersity. E jowo e tunbo se alaye lekunrere itunmo WikiVersity atipe ipa wo ni e fe ki a ko ninu re.Sowoletoyin (ọ̀rọ̀) 07:44, 1 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)

Wikiversity Yoruba je ile-eko lori intaneti. Ọ je pẹpẹ eko ti ohun se iranlowo fún awon omo ile-iwe. Ṣiṣẹda Wikiversity Yoruba n se isẹ nla fun awa ọmọ oduduwa. Mo fe ki Yoruba le wo Wikiversity ni ede tiwantiwa Yoruba. Mo fe ki ema ka ewe ni Yoruba ati ki a le ko awon ara ita ni Yoruba. Ni idaniloju lati so asoye ati lati so imoran, ogbon,imo ati oye pelu olugbekale ati oludasile Wikiversity Yoruba Project.Tbiw (ọ̀rọ̀) 13:59, 1 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)

Ipa ti mo fe ki e ko ninu re ni pe ki e ba mi je ọ ṣe aseyori. Ki e se atileyin rẹ ki e dé tun ba mi ko akoonu. Tbiw (ọ̀rọ̀) 14:04, 1 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)