Ọ̀tọ̀-Àwórì
Àgbègbè ìdàgbàsókè àti ìlú ní Ìpínlẹ̀ Èkó
Ọ̀tọ̀-Àwórì je ijoba idagba-soke agbegbe ijoba ibile Ojo, ti o wa ni opopona marose Èkó si Agbada-rigi.[1][2]
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ó wà nibẹ̀
àtúnṣe- Adeniran Ogunsanya College of Education
- National Postgraduate College of Nigeria[3]
Ẹ tuń lè wo
àtúnṣe- History of Lagos
- Awori District settlements