Ọjọ́ Àbámẹ́ta

Ọjọ́ Àbámẹ́ta tabi Satide tí wọ́n tún ń pe ní diēs Sāturnī ("Saturn's Day") je òpin ọjọ́ ọ̀sẹ̀ tí ó wà láàrín ọjọ́ Ẹtì àti Ọjọ́ Àìkú. [1][2]

Ọjọ́ Àbámẹ́ta ni ọjọ́ keje tí ó kẹ́yìn nínú ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá.  1. Falk, Michael (June 1999), "Astronomical Names for the Days of the Week", Journal of the Royal Astronomical Society of Canada, 93: 122–133, Bibcode:1999JRASC..93..122F 
  2. Vettius Valens (2010) [150–175], Anthologies (PDF), translated by Riley, Mark, Sacramento State, pp. 11–12