Ọláídé Ọláògún
Ọláídé Ọláògún tí a tún mọ̀ síỌláídé Omololá Ọláògún Emmanuel tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1986,(July 9, 1986) jẹ́ Òṣèrébìnrin, Afẹ́wà-ṣojú àti Atọ́kùn ètò ọmọ Nàìjíríà. Ó ti fìgbà kan jẹ́ Afẹ́wà-ṣojú oṣẹ Lux [1]
Ọláídé Ọláògún | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | July 9, 1986 Lagos |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Ọláídé Ọláògún Emmanuel |
Ẹ̀kọ́ | African Church Model College, University of Lagos |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin, Afẹ́wà-ṣojú àti Atọ́kùn ètò |
Gbajúmọ̀ fún | Sinimá àgbéléwò |
Olólùfẹ́ | Babatúndé Ọ̀jọrá Emmanuel |
Àwọn ọmọ | Ọmọ kan |
Ìgbésí-ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ọláídé Ọláògún ní ìlú Èkó lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1986.[2] Ó kàwé ní African Church Model College. Bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè nínú èdè Òyìnbó ní University of Lagos.[3]
Ó di gbajúmọ̀ òṣèré ní Nàìjíríà àti Ghana nígbà tí ó kópa nínú eré kan tí Wale Adenuga gbé jáde lórí tẹlifíṣàn, ti àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Soul Sisters" [4] and she was also in the Yoruba series Super Story.[3]
Lọ́dún 2007, ó gba ipò Genevieve Nnaji gẹ́gẹ́ bí afoge-ṣojú nínú ìpolówó-ọjà ọṣẹ Lux[5] and continued in this role until 2009.[2] Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ afoge-ṣojú ilé iṣẹ́ aṣerunlóge, Diva hair extension, Fuman juice àti Ilé-ìfowópamọ́ United Bank for Africa (UBA).[4]
Ìgbésí-ayé ara rẹ̀
àtúnṣeỌláídé fẹ́ Babátúndé Ọ̀jọrá Emmanuel lọ́kọ lọ́dún 2015[6] wọ́n sìn bímọ kan péré fún ara wọn lọ́dún 2016. She was married to Babatunde Ojora in 2019.[1]
Àtẹ àṣàyàn àwọn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Sinimá | Ẹ̀dá-ìtàn | Àkíyèsí |
---|---|---|---|
2005 | Omoye | Racheal | |
2005 | A new Song | Juliet | |
2006 | Elulu Tafajo | Tayo | |
2006 | Lion of Mogun | Série télé | |
2006 | Odu | ||
2006 | Iyawo Afoju | ||
2007 | Everything it takes | ||
2007 | Elerin Eye | Mopelola | |
2008 | Tinsel | ||
2008 | Eleburu Ike | ||
2009 | Atehinbo | ||
2009 | The Perfect Church | ||
2010 | Hands of a Stranger | Tokunbo Babs Oshodi | |
2010 | The Promise | Ego | |
2011 | Obi Eni | ||
2011 | Valentine | Rose | |
2013 | Memuna Gbagi |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Actress Olaide Olaogun's Marriage Ends Over Allegations Of Domestic Violence". Within Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-10. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ 2.0 2.1 Philippe. "Olaide Olaogun a nigerian actress". artetcinemas.over-blog.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-04-28.
- ↑ 3.0 3.1 "Nothing wrong in kissing or romancing on stage----Olaide Olaogun". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-28.
- ↑ 4.0 4.1 "He helped fix my flat tyre and became my husband – Olaide Olaogun, actress". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-21. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ "Fashion should be simple — Kehinde Bankole". punchng.com. Archived from the original on 29 November 2014. Retrieved 18 November 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Babatunde Emmanuel Ojora - OnoBello.com". onobello.com. Archived from the original on 2021-11-22. Retrieved 2020-04-28.