Abass Adigun
Olóṣèlú
Abass Adigun Agboworin je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju ti o n sójú Ibadan North-East / Ibadan South-east ti Ìpínlẹ̀ Ọyọ ni Ile-igbimọ Aṣofin Agba kẹwàá. [1] [2] [3] [4]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://tribuneonlineng.com/icons-abass-adigun-agboworin/
- ↑ https://www.thecable.ng/pdps-agboworin-defeats-lam-adesina-to-take-oyo-rep-seat/
- ↑ https://thenationonlineng.net/group-knocks-agboworin-for-allegedly-disrespecting-pdp-deputy-nchair/
- ↑ https://businessday.ng/news/article/oyo-tribunal-affirms-adiguns-victory-dismisses-apcs-petition/