Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìlàòrùn Ìbàdàn

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìlàòrùn Ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní gbọ̀ngán Mapo. Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ ìlú náà ni 200.[1]

Ibadan South-East
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilEmmanuel Oluwole Alawode (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ìwọ̀n ilẹ̀

àtúnṣe

Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 17 km2 àti iye ènìyàn tó tó 266,046 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)