Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìlàòrùn Ìbàdàn
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ibadan North-East (Yoruba: Ariwa-Ilaorun Ibadan) jẹ́ àgbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olú ilẹ̀-iṣẹ́ wọn wá ní Ìwó Road. Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà ìránṣẹ́ sí tí agbègbè náà ni 200.[1]
Ibadan North-East Ariwa-Ilaorun Ibadan | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Ibrahim Akintayo (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ìwọ̀n ilẹ̀
àtúnṣeÓ ní ìwọ̀n ilẹ̀ tí 18 km2 àti iye àwọn ènìyàn tó jẹ́ 330,399 ni ètò ìkànìyàn 2006.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àdàkọ:Coord missing Àdàkọ:LGAs and communities of Oyo State Àdàkọ:Authority control