Abdulkadir Mohammed Nasir

Abdulkadir Mohammed Nasir (ojoibi 6 osu kini ọdun 1965) je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Naijiria to ṣíṣe gẹ́gẹ́ bi ọmọ ile-igbimọasofin to nsójú àwọn àgbègbè Katsina/MalumFashi/Kafur lati odun 2007 si 2011 labe egbe oselu People's Democratic Party . [1]

Abdulkadir Mohammed Nasir
Member of the House of Representatives of Nigeria from Katsina State
In office
2007–2011
ConstituencyKatsina/MalumFashi/Kafur
Àwọn àlàyé onítòhún
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
OccupationPolitician

Àwọn ipò ti odi mun

àtúnṣe

Abdulkadir Mohammed Nasir ni a yàn gẹgẹbi olutọju orilẹ-ede fun Eto Idoko-owo Awujọ ti Orilẹ-ede (NSIP) nipasẹ Muhammadu Buhari . [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe