Abdulkarim Usman jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlè Nasarawa tó ń ṣojú àwọn ẹkùn ìdìbò Akwanga/Nasarawa/Eggon/Wamba láti ọdún 2019 sí 2023 lábẹ́ ìpìlẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party . [1] OỌdún 970 ni wwọn i Usman. O wa lláti ìpínlè Nasarawa. [2]

Abdulkarim Usman
Member of the House of Representatives of Nigeria from Nasarawa State
In office
2019–2023
ConstituencyAkwanga/Nasarawa/Eggon/Wamba
Àwọn àlàyé onítòhún
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
OccupationPolitician

Awọn itọkasi

àtúnṣe