Abiola Ajimobi

Olóṣèlú Nàìjíríà, Gomina tẹlẹri ni ipinlẹ Ọyọ

Isiaka Abiola Ajimobi (ojóìbí 16 December 1949-2020) jé olósèlú omo orílè-èdè Naijiria àti gómìnà Ipinle Oyo láti 29 Osù Karun 2011 titi di 2019. Ó tun jé Alàgbà ni Ile Alagba Asofin Naijiria láti 2003 de 2007.

Isiaka Abiola Adeyemi Ajimobi
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
In office
29 May 2011 – 29 May 2019
AsíwájúChristopher Alao-Akala
Arọ́pòOluwaseyi Makinde
Senator for Oyo South
In office
May 2003 – May 2007
AsíwájúPeter Olawuyi
Arọ́pòKamorudeen Adekunle Adedibu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kejìlá 1949 (1949-12-16) (ọmọ ọdún 74)
Oja'ba, Ibadan, Oyo State, Nigeria
Aláìsí25 June 2020(2020-06-25) (ọmọ ọdún 70)
Lagos, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)