Oluseyi Makinde
Olusèyí Abiọ́dún Mákindé ni a bí ní ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1967 (25 December 1967). Ó jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú àti ọlọ́rẹ àtinúwá Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà tí ó ń bẹ lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1] ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Wọ́n dìbò yàn-án ní Ọdún 2019 lábé àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) Ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas Metering).[3]
Oluseyi Abiodun Makinde | |
---|---|
Present Governor of Oyo State in His Office | |
Gomina Ipinle Oyo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2019 | |
Asíwájú | Abiola Ajimobi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oluwaseyi Abiodun Makinde 25 Oṣù Kejìlá 1967 Ibadan |
Aráàlú | Nigerian |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Tamunominini Makinde |
Àwọn ọmọ | 3 |
Ìyá | Abigail Makinde [citation needed] |
Bàbá | Olatubosun Makinde [citation needed] |
Education | University of Lagos |
Occupation | Politician, Engineer |
Known for | Group Managing Director of Makon Group Limited |
Ibere pepe aye re ati eko
àtúnṣeA bi makinde si ile Pa Olatubosun Makinde, ati Abigail Makinde ni adugbo Aigbofa, Oja’ba, ni ilu Ibadan, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ọ̀un ni awon obire bi siketa.[2][3] Makinde bere eko re ni Ile eko-ibere St Paul primary school. O pari eko- Ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ni St Michael Primary School,ni Ye metu. Makinde se eko girama ní Bishop Phillips Academy[4]. Ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ìlú Èkó níbi tó ti gba ìwé-ẹrí bachelor degree nínú ìmò Electrical Engineering.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ https://www.vanguardngr.com/2019/03/oyo-guber-pdp-clears-28-lgs-to-dislodge-apc-as-makinde-emerges-gov-elect/amp/
- ↑ 2.0 2.1 "Nigeria: Makinde - Profile of Oyo Guber PDP Aspirant". allafrica.com. 21 September 2014. http://allafrica.com/stories/201409220019.html. Retrieved 21 May 2016.
- ↑ 3.0 3.1 BISI, OLADELE (23 December 2015). "Oyo 2015: Four Ibadan indigenes for governor". The Nation Online NG. http://thenationonlineng.net/oyo-2015-four-ibadan-indigenes-governor/. Retrieved 21 May 2016.
- ↑ "ICONS: Seyi Makinde". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-29. Retrieved 2022-03-01.