Abu Salman Shahjahanpuri
Abu Salmān Shahjahānpūri tí orúkọ àbísọ ń jẹ́ Tasadduq Hussain Khan ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kiní ọdún 1940 ní Shahjahanpur.[1]
Ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeAbu Salmān Shahjahānpūri tí orúkọ àbísọ ń jẹ́ Tasadduq Hussain Khan ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kiní ọdún 1940 ní Shahjahanpur.[1][2] Ó lọ sí í ilé ìwé ní Madrasa Saeedia ní
Shahjahanpàti ti Jamia Qasmia Madrasa Shan ní Morada. Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́wàá, Ó ṣí lọ ío Pakian ninu ọdún 1950.0.[3] Ó gba BA àti MA dìgígì/iyì láti Ilé-ìwé gíga tí Karachi ó sì parí ìmọ̀ ẹ̀kọ́ dókítà a rẹ̀ ní Ilé-ìwé gíga Sindh.[3][1] Kókó ìdí pàtàkì i ìmò dókítà a rẹ̀ ni láti ṣàkójọpọ̀ àti ka Khānwada-e-Waliullāhi ti Syed Ahmad Khan.[4]
Shahjahānpūri sìn/ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ọjọ̀gbọ́n fún Government National College, Karachi ó sì fẹ̀yìntì lénu iṣẹ́ nínu odùn 2002.[5][1] A kà á yẹ sí Aláṣẹ lórí i ìtàn-Àkọọ́lẹ̀ àti ètò Òṣèlú ti Ìlú u Indian.[6] Ó ní ǹkan ṣe pẹ̀lú Abul Kalam Azad ṣèwádìí ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó tún ṣàbẹ̀wo India nígbà 2014 láti pèsè àwọn ìwé rẹ̀ ní ìlú àwọn ọlùmọ̀wé tí òkèèrè nípa Abul Kalam Azad àwọn aláṣẹ àwùjọ Iran ṣe ètò àti Maulan Ab̀ul Kalam Azad Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Asian Studies ní Kolkata.[7] Ìtàn-àkọ̀ọ́lẹ̀ ẹ rẹ̀ jẹ yọ nínu Ma'ārif ti Ilé-ẹ̀kọ́ ọ Shibli , ti Burhān ti Nadwatul Musannifeen, Madina àti ti Chattan.[2] Nínú ọdún 2010, Ó fi ìwé tí ó ti kọ tí ó sì ju ẹgbẹ̀rún kan lọ, kún iyì í rẹ̀.[6] Ó dáwọ́ ìwé kíkọ dúró nínú ọdún 2016 nítorí àìlera a rẹ̀ àti ogbó ọjọ́ orí í rẹ.
Shahjahānpūri, Wọ́n dáná sun ilé rẹ̀ nígbà tí Qasba Aligarh massacre ní ọdún 1986. Gẹ́gẹ́ bí i 2019 Ìròyìn Pópónà fẹsùn kàn, pé ẹgbẹ̀rún iṣẹ́ ni ó bọ́ nípasẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ àti àwọn ìwé tí ó jẹ́ ohun-ìní i rẹ̀.[2]
Abul Kalamism
àtúnṣeShahjahānpūri ni wọ́n gbà bí “Abul Kalāmi” pàtàkì ní Pakistan lẹ́hìn Agha Shorish Kashmiri àti Ghulam Rasool Mehr.[8] Ó bẹ̀rẹ̀ kíkọ ìwé sílẹ̀ ní ọdún 1957, àti pé átíkù àkọ́kọ́ rẹ̀ hàn lẹ́hìn ikú Abul Kalam Azad. Ó ṣe kóódù oríṣiríṣi àwọn ìwé àkọsílẹ̀ (átíkù) ti Azad ó sì jẹ́ kí wọ́n ṣe àtẹjáde ẹ̀.[8] Ó kọ àwọn àkọsílẹ̀ àlàyé sí ìtumọ̀ Urdu ti Azad's India Wins Freedom".[8] Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí Azad pẹ̀lú Maulana Abul Kalam Azad: Ek Siyasi Mutala, Maulana Abul Kalam Azad: Ranchi mai nazarbandi awr uska faizān, Maulana Abul Kalam Azad awr Khwajah Hasan Nizami, Maulana Abul Kalam Azad ke chand buzurg ati Abul Kalam Azad awr un 'àsirin.[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 Inayat Shamsi (2 February 2021). "کراچی: 150 سے زائد کتابوں کے مصنف ابو سلمان شاہجہان پوری چل بسے" (in ur). Alert News. Archived from the original on 9 February 2021. https://web.archive.org/web/20210209063347/https://alert.com.pk/archives/27674.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Rizwan Tahir Mubeen (5 March 2019). "تحقیق میں خود نمائی سے دور رہا، بطور مرتب بھی نام آنا اچھا نہیں لگتا، ڈاکٹر ابو سلمان" (in ur). Express News. https://www.express.pk/story/1577412/1/.
- ↑ 3.0 3.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedarynews
- ↑ Abdullah Shamim Qasmi (2 February 2021). "ايک چراغ اور بجھا نامور محقق ومصنف ڈاکٹر ابو سلمان شاہجہانپوری كى وفات" (in ur). Baseerat Online. https://www.baseeratonline.com/135110.
- ↑ Javed Ahmad Khurshid (January–June 2019), "Kitābiyāt, Tasānī, maqālat wa dīgar az Dr Abu Salman Shahjahanpuri" [Abu Salmān Shahjahānpūri bibliography], Tehseel (4): 199
- ↑ 6.0 6.1 Uzaira Khan (18 October 2010). "History in a different perspective". Dawn. https://www.dawn.com/news/573194.
- ↑ "International seminar to mark Maulana Azad's 125th birth anniversary". Business Standard. 2 September 2014. https://www.business-standard.com/article/news-ians/international-seminar-to-mark-maulana-azad-s-125th-birth-anniversary-114090200918_1.html.
- ↑ 8.0 8.1 8.2 Khalid Humayun (19 December 2012). "ڈاکٹر ابوسلمان شاہجہانپوری کی ابوالکلامیاں" (in ur). Daily Pakistan. https://dailypakistan.com.pk/19-Dec-2012/31741.
- ↑ Javed Ahmad Khurshid (January–June 2019), "Kitābiyāt, Tasānīf, maqālat wa dīgar az Dr Abu Salman Shahjahanpuri" [Abu Salmān Shahjahānpūri bibliography], Tehseel (4): 200–206