Adéńrelé Ṣónáriwo

Adéńrelé Ṣónáriwo jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣòwò àti atọ́kùn nǹkan ìṣẹ̀m̀báyé àti iṣẹ́-ọ̀nà. Òun ni olùdáaílẹ̀, ilé-iṣẹ́ iṣẹ́-ọ̀nà, Rele Art Gallery tí ó wà ní Military Street, Onikan, Erékùṣù Èkó, ní Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni olórí atọ́kùn ìṣẹ̀m̀báyé fún tó ṣojú Nàìjíríà lọ́dún 2017 níbi ìpàtẹ Venice Biennale ẹlẹ́kẹtàdínlọ́gọ́ta.

Adéńrelé Ṣónáriwo
Ọjọ́ìbíNàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaHoward University, Academy of Art University, University of the Arts London
Iṣẹ́Curator, Entrepreneur

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Adéńrelé Ṣónáriwo kàwé gboyè dìgírì àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ ìṣirọ̀-owó ní Howard University, lẹ́yìn èyí, ó ṣiṣẹ́ ní PricewaterhouseCoopers gẹ́gẹ́ bí Aṣírò-owóan fún ọdún mẹ́rin.[1][2] Ó kàwé gboyè MA nínú ìmọ̀ Multimedia Communications ní ilé ẹ̀kọ́, Academy of Art University, bẹ́ẹ̀ ó ní ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ atọ́kùn ìṣẹ̀m̀báyé àti iṣẹ́-ọ̀nà láti University of the Arts London.[2]

Ilé ìpàtẹ iṣẹ́-ona Relé

àtúnṣe

Bí ó ṣe padà sí Nàìjíríà, ó dá Ilé ìpàtẹ iṣẹ́-ona sílẹ̀, tí ó pè ní Rele Art Gallery lọ́dún 2010, ilé-isẹ́ kò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àfi ọdún 2015,ti ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fi lọ́lẹ̀ gan-an.[2] Lọ́dún 2011,nígbà tí ó gbèrò ìdásílẹ̀ ilé yìí, ó gbà á lérò láti dá a sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí yunifásítì ní Nàìjíríà, tí yóò pè ní;The Modern Day School of the Arts.[3][1] Ó jẹ́ ilé ìwé fún àwọn olólùfẹ́ iṣẹ́-ọ̀nà, tí yóò máa wá dábírà ẹ̀bùn isẹ wọn."[4]

Ìpàtẹ Venice Biennale ẹlẹ́kẹtàdínlọ́gọ́ta

àtúnṣe

Lọ́dún 2017, Ṣónáriwo ni ó darí ikọ̀ àwọn atọ́kùn ìṣẹ̀m̀báyé ti Nàìjíríà ní Ìpàtẹ Venice Biennale ẹlẹ́kẹtàdínlọ́gọ́ta.[5][6] Ẹni tí ó ṣìkejì rẹ̀ ni àgbà oǹkọ̀wé àti aṣelámèyítọ́ iṣẹ́-ọ̀nà, Emmanuel Iduma gẹ́gẹ́ ní igbákejì atọ́kùn. Àkọlé ètò ìpàtẹ náà ni Viva Arte Viva[7][4] ètò ìpàtẹ náà pàtẹ àwọn iṣẹ́ gbajúmọ̀ oníṣẹ́-ọ̀nà bí i: Victor Ehikhamenor, Peju Alatise, àti Qudus Onikeku.[8][9][10]

Àwọn àmìn-ẹ̀yẹ

àtúnṣe

Ṣónáriwo gbàmìn ẹ̀yẹ àṣà àti ìṣe lọ́dún 2016.[11] Bẹ́ẹ̀ náà ló wà lára àwọn adarí àṣà lọ́dún 2016 [12] and 2017.[13] Lóṣù kẹta ọdún 2017, wọn yàn án lára àwọn ọgọ́rùn-ún amóríyá obìnrin ní Nàìjíríà. (100 Most Inspiring Women in Nigeria) .[14] Ó jẹ́ asọ̀rọ̀ ní ètò TEDx,[15] bẹẹ náà ló jẹ́ adájọ́ ètò ìdíje Dak'art Biennale tó wáyé lọ́dún 2018.[16] Wọ́n ti fìgbà kan fi àwòrán rẹ̀ ṣe olú-àwòránt fún ìwé ìròyìn olóṣooṣù (Guardian Life magazine) ní Nàìjíríà .[17]

Lọ́dún 2018, ilé iṣẹ́ Vogue dárúkọ rẹ̀ mọ́ àwọn "Five Coolest Women in Lagos"[18]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "I Am Creative With Adenrele Sonariwo" (in en-US). Archived from the original on 2017-12-01. https://web.archive.org/web/20171201032803/https://guardian.ng/life/spotlight/i-am-creative-with-adenrele-sonariwo/. 
  2. 2.0 2.1 2.2 "From Accountant to Art Curator! Rele Art Gallery's Adenrele Sonariwo is our #BellaNaijaWCW this Week - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-11-25. 
  3. Nescafé (2017-04-11). "Why Adenrele Sonariwo Quit Her Auditing Job To Launch An Art Gallery" (in en-US). Konbini Nigeria. Archived from the original on 2019-07-01. https://web.archive.org/web/20190701145413/http://www.konbini.com/ng/inspiration/why-adenrele-sonariwo-quit-her-auditing-job-to-launch-an-art-gallery/. 
  4. 4.0 4.1 "Adenrele Sonariwo; The Art Lover and Brain behind The Rele Gallery" (in en-US). Konnect Africa. 2017-09-08. http://www.konnectafrica.net/adenrele-sonariwo/. 
  5. name, Site. "The Venice Questionnaire #22 – Adenrele Sonariwo / ArtReview". artreview.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-11-25. 
  6. "56 editions after, Nigeria debuts at Venice Biennale - Premium Times Nigeria" (in en-GB). Premium Times Nigeria. 2017-03-28. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/artsbooks/227340-56-editions-nigeria-debuts-venice-biennale.html. 
  7. "57th International Art Exhibition - Viva Arte Viva" (in en). La Biennale di Venezia. 2017-03-09. http://www.labiennale.org/en/news/57th-international-art-exhibition-viva-arte-viva. 
  8. "See the Highlights from Nigeria's Debut at the Most Important Art Exhibition in the World - La Biennale di Venezia - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-11-25. 
  9. "Nigeria unveils first national pavilion at Venice art exhibition" (in en-US). Archived from the original on 2017-11-28. https://web.archive.org/web/20171128025545/https://guardian.ng/art/nigeria-unveils-first-national-pavilion-at-venice-art-exhibition/. 
  10. Orubo, Daniel (2017-03-24). "Meet The Nigerian Artists Set To Make History At The Venice Biennale" (in en-US). Konbini Nigeria. Archived from the original on 2019-07-01. https://web.archive.org/web/20190701145412/http://www.konbini.com/ng/inspiration/meet-the-nigerian-artists-set-to-make-history-at-the-venice-arte-biennale/. 
  11. "See the inspiring profiles of the winners of The Future Awards Africa 2016 - The Future Awards Africa" (in en-GB). The Future Awards Africa. 2016-12-18. http://thefutureafrica.com/awards/see-inspiring-profiles-winners-future-awards-africa-2016/. 
  12. YManager (August 5, 2016). "LAOLU SEBANJO, DAMILOLA ELEBE, ADENRELE SONARIWO… SEE THE #YNAIJAPOWERLIST FOR CULTURE". YNaija. https://ynaija.com/laolu-sebanjo-damilola-elebe-adenrele-sonariwo-see-ynaijapowerlist-culture/. 
  13. "Bovi, Wana Udobang, Osa Seven… See the #YNaijaPowerList2017 for Culture » YNaija". ynaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-07-16. 
  14. Editor (March 8, 2017). "AMINA MOHAMMED, MO ABUDU, SOMKELE IDHALAMA & MORE! YNAIJA.COM AND LEADING LADIES AFRICA PRESENT THE 100 MOST INSPIRING WOMEN IN NIGERIA". YNaija. https://ynaija.com/ynaija-com-leading-ladies-africa-present-100-inspiring-women-nigeria/. 
  15. "Tedx: Ibara Set To Hold The First Tedx In Abeokuta City - The Bees NG" (in en-US). The Bees NG. 2018-04-16. Archived from the original on 2019-07-01. https://web.archive.org/web/20190701150922/http://thebeesng.com/tedx-ibara-set-to-hold-the-first-tedx-in-abeokuta-city/. 
  16. "Dak'art 2018 – Biennale de Dakar Edition 2018". biennaledakar.org (in Èdè Faransé). Archived from the original on 2018-07-16. Retrieved 2018-07-16.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. "Nigeria: Adenrele Sonariwo Covers Guardian Life Magazine" (in en-US). News of Africa - Online Entertainment - Gossip - Celebrity Newspaper - Breaking News. 2018-01-29. Archived from the original on 2018-07-16. https://web.archive.org/web/20180716224152/https://newsofafrica.org/229780.html. 
  18. "Meet the 5 Coolest Women in Lagos" (in en). Vogue. https://www.vogue.com/article/lagos-nigeria-fashio-instagram-it-girls.