Adeyemi Afolayan
Òṣéré orí ìtàgé
(Àtúnjúwe láti Adéyẹmí Afọláyan)
Kunle Afolayan (ti atun mo si Ade Love)[1] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òṣèré àti olùdarí sinimá-àgbéléwò lédè Yoruba.[2] Ó jẹ́ arákùnrin sí òṣèré Toyin Afolayan, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ bàbá sí àwọn òṣèré bí i, Kúnlé Afọláyan, Gabriel Afọláyan, Mojí Afọláyan àti Àrẹ̀mú Afọláyan.[3]
Ade Love | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Adeyemi Josiah Afolayan 1940 Ìpínlẹ̀ Kwara |
Aláìsí | 1996 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1976-1996 |
Notable work | Ajani Ogun (1976) |
Àwọn ọmọ |
|
Àwọn olùbátan | Toyin Afolayan (sister) |
Afọláyan darapọ̀ mọ ẹgbẹ́ tíátà ti Musa Olaiya, ni ọdun 1971, ó fi í sílẹ̀ láti dá ẹgbẹ́ tirẹ sílẹ̀ lábala eré aláwàdà.
Àtòjọ díẹ̀ lára àwọn eré rẹ̀
àtúnṣe- Taxi Driver (1983)
- Ajani Ogun (1976)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 28 February 2015. Retrieved 27 February 2015.
- ↑ "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 28 February 2015. Retrieved 28 February 2015.
- ↑ "Saying I'm beautiful is flattery". Nigerian Tribune Newspaper. Retrieved 28 February 2015.