Kunle Afolayan
Kunle Afolayan (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé, Adeyemi Afolayan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love[1] [2]
Kunle Afolayan | |
---|---|
Kunle Afolayan at the 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kẹ̀sán 1974 Ebute Metta, Lagos State, Nàìjíríà |
Ibùgbé | Magodo, Ikeja, Lagos State, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | |
Olólùfẹ́ | Tolu Afolayan |
Àwọn ọmọ | 4 |
Parent(s) | Ade Love - father |
Àwọn olùbátan |
|
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
àtúnṣeKúnlé jẹ́ ọmọ bíbí Ìgbómìnà pọ́ńbélé láti ìpínlẹ̀ Kwara gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú. Gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò àná ni bàbá rẹ̀ Ade Love. Kúnlé kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìsúná ọ̀rọ̀-ajé. Ó ṣiṣẹ́ nílé ìfowópamọ́ fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe sinimá àgbéléwò ṣíṣe lọ́dún 2015. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti ń kópa ní ìwọ̀nba kí ó tó di àkókò yìí. Kúnlé máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa tó ṣòódó. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sìn ni àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà gẹ́gẹ́ bí eléré tíátà.[3] [4]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeYear | Film | Role | Notes | Ref | |||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Actor | Director | Producer | Writer | ||||
1999 | Saworoide | Yes | |||||
2002 | Agogo Eewo | Yes | |||||
2005 | Ti Ala Ba Ku | Yes | |||||
2006 | Irapada | Yes | Yes | Yes | Yes | [5] | |
Èjiwòrò | Yes | ||||||
2007 | Onitemi | Yes | |||||
2009 | The Figurine | Yes | Yes | [6] | |||
Farayola | Yes | ||||||
2012 | Phone Swap | Yes | Yes | Yes | [7] | ||
2014 | Dazzling Mirage | Yes | [8] | ||||
1 October | Yes | Yes | Yes | [9] | |||
2016 | The CEO (fíìmù 2016) | Yes | Yes | [10] | |||
2017 | The Bridge | Yes | Yes | [11] | |||
Omugwo | Yes | Yes | [12] | ||||
2018 | Crazy People | Yes | |||||
2019 | Mokalik | Yes | Yes | [13] | |||
Diamonds in the Sky | Yes | [14] | |||||
2020 | Citation | Yes | [15][16] | ||||
2021 | Ayinla | Yes | [17] | ||||
Swallow | Yes | Yes | Yes | Yes | [18] | ||
A Naija Christmas | Yes | [19] | |||||
2022 | Anikulapo | Yes | Yes | Yes | |||
2023 | Ijogbon [20] | yes |
Awọn àmì ẹ̀yẹ
àtúnṣeYear | Award | Category | Film | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Best of Nollywood Awards | Director of the Year | Diamond in the Sky | Wọ́n pèé | [14] |
2021 | Net Honours | Most Searched Actor | Wọ́n pèé | [21] | |
2023 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Indigenous Language – Yoruba | Anikulapo | Gbàá | [22] |
Best Movie West Africa | Yàán | ||||
Best Overall Movie | Gbàá | ||||
Best Director | Yàán |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Kunle Afolayan Biography, History, Asset and Net Worth - Austine Media". Austine Media. 2018-05-20. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "Kunle Afolayan". Leadership Newspaper. 2019-04-07. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ Hoad, Phil (2012-10-30). "Out of Africa: Kunle Afolayan bids to bring Nollywood cinema to the world". the Guardian. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "BIOGRAPHY". OKIKI AFOLAYAN CONCEPTS. 2018-01-31. Archived from the original on 2019-12-09. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "Leila Djansi's Sinking Sands Listed On CNN Among 10 Must-See African Films". news1ghana.com. Retrieved 22 October 2014.
- ↑ Obenson, Tambay A. (28 October 2013). "Halloween 2013 Countdown - Nigerian Director Kunle Afolayan's Horror/Thriller 'The Figurine'". IndieWire. Shadow and Act. Archived from the original on 26 April 2014. Retrieved 25 April 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:1
- ↑ Nwanne Chuks (28 June 2014). "Lala Dazzles In Kelani's Dazzling Mirage". The Guardian (Nigeria). Archived from the original on 12 August 2014. Retrieved 7 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedCEOunveil
- ↑ nollywoodreinvented (13 September 2019). "The Bridge". Nollywood REinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 November 2019.
- ↑ "Kunle Afolayan, Omowunmi Dada, Ayo Adesanya attend media screening". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 April 2017. Retrieved 3 November 2019.
- ↑ "Movie Review: Kunle Afolayan's 'Mokalik' thrives on memory, not viewer satisfaction" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 November 2019. Retrieved 6 May 2020.
- ↑ 14.0 14.1 Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Augoye, Jayne (3 November 2020). "Kunle Afolayan screens 'Citation' in Lagos". Premium Times. Retrieved 7 November 2020.
- ↑ Report, Agency (8 July 2022). "Kunle Afolayan's Citation wins 'Best International Film' in UK award". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 29 July 2022.
- ↑ Nwogu, Precious (14 December 2020). "Tunde Kelani announces production of Ayinla Omowura biopic titled 'Ayinla'". Pulse Nigeria. Retrieved 12 May 2021.
- ↑ "Swallow (2021) review – this is hard to swallow.". Ready Steady Cut. October 2021. Retrieved 2 October 2021.
- ↑ Kennedy, Lisa (16 December 2021). "'A Naija Christmas' Review: Honoring a Mother's Wish - The New York Times". https://www.nytimes.com/2021/12/16/movies/a-naija-christmas-review.html. Retrieved 16 December 2021.
- ↑ "Ijogbon", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 15 October 2023, retrieved 18 October 2023
- ↑ "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07.
- ↑ "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]