Ada Ameh
Ada Ameh jẹ́ òṣèré ará ìlú Nàìjíríà kan tí ó ti lò ju ọdún ogún lọ ní ilé-iṣẹ fíìmù ti Nàìjíríà àti pé ó ṣe àkíyèsí jùlọ fún ipa rẹ̀ bi Anita ni fiimu 1996 tí àkọlé rẹ̀jẹ́ “ Domitilla” àti bi Emu Johnson nínú eré aláàmì-ẹ̀ye ti àkọlé rẹ jẹ́ Johnsons . Ameh nínu The Johnsons ṣe ìfihàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn òṣèré Nollywood mìíràn bii Charles Inojie, Chinedu Ikedieze & Olumide Oworu .[2][3][4]
Ada Ameh | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ada Ameh May 15 Ajegunle, Lagos State |
Aláìsí | 17 July 2022[1] Warri, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1995-Present |
Àwọn ọmọ | 1 |
Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́
àtúnṣeAmeh, bótilẹ̀jépé o jẹ́ abínibí ti Idoma ni Ipinle Benue, a bí tí o si dàgbà nìi Ajegunle ni Ipinle Eko, apá ìhà ìwọ-oòrùn gúúsù ìwọ-oòrùn ti Nàìjíríà tí ó borí púpọ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn tí n sọ èdè Yorùbá ti Nigeria . Ameh gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé alàkọ̀bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé giga ni ipinlẹ Eko ṣùgbọ́n óó parí ilé-ìwé ọjọ́-orí 14.[5]
Iṣẹ́
àtúnṣeAmeh Ní ọdún 1995 ní ìfọwọ́sí apákan ti ilé-iṣẹ́ fíìmù ti Nollywood àti gba ipò fíìmù àkọ́kọ́ rẹ ní ọdún 1996 níbití ó ti kópa bí Anita ní fiimu “Domitila” Fíìmù kan tí ó di iṣẹ́ àṣeyọrí . Fíìmù náà ṣe àgbékalè àti ṣe ìtọ́sọ́nà nípasẹ̀ Zeb Ejiro . Ameh tún ṣe ìfihàn nínu jara TV ti Nàìjíríà tí àkọ́lé rè jẹ́ the Johnsons èyítí o tun di iṣẹ́ àṣeyọrí tí ó gba àwọn àmì-ẹri .[6][7]
Igbésí ayé ara ẹni
àtúnṣeAmeh Ní ọmọ obìnrin kan tí ó bí ní gbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá. Ameh jẹ ẹniti ó ń sọ èdè míràn ati èdè abinibi agbègbè rẹ̀ ní èdè Idoma, Gẹẹsi, Yoruba ńsọ ọ́pọ́ èdè àtioèdèNí ọdún 2017 wón gbé àkọle olórí fún Ameh ni Ipinle Benue[8][9]
Filmography tí ayàn
àtúnṣe- Domitila
- Aki na Ukwa (pẹ̀lú Osita Iheme & Chinedu Ikedieze)[10]
- Phone Swap (pẹ̀lú Wale Ojo, Chika Okpala, Nse Ikpe-Etim & Joke Silva)[11]
- Blood Money' '[12]
- Atlas Oloture
- Our Husband
- King Of Shitta
- Ghana Must Go[13]
- A Million Baby[14]
- One Good Turn
- Double Trouble
Eré Tẹlifiṣọ̀nù
àtúnṣe- The Johnsons[15]
Àkópó Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ada Ameh burial: Tears flow as dem bury di late Nigerian actress". BBC News Pidgin. August 26, 2022. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ https://www.pmnewsnigeria.com/2018/09/17/the-johnsons-cast-win-city-peoples-movie-awards/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-12-03. Retrieved 2020-10-17.
- ↑ https://punchng.com/my-father-cried-when-i-got-pregnant-at-14-ada-ameh/
- ↑ https://allure.vanguardngr.com/2018/04/i-dropped-out-of-school-at-age-14-actress-ada-ameh/
- ↑ https://africamagic.dstv.com/actor/ada-ameh
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-05-24. Retrieved 2020-10-17.
- ↑ https://punchng.com/i-did-not-lose-weight-to-please-men-ada-ameh/
- ↑ https://www.informationng.com/2017/11/johnsons-actress-ada-ameh-lands-chieftaincy-title-benue-state.html
- ↑ https://austinemedia.com/ada-ameh-biography-and-net-worth/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ https://medium.com/the-nerveflo-post/phone-swap-the-nollywood-movie-review-8a94c93b56ce
- ↑ https://keninfo.com.ng/2020/01/31/actress-ada-ameh-biography-and-net-worth/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-18. Retrieved 2020-10-17.
- ↑ https://www.pulse.ng/entertainment/movies/a-million-baby-watch-odunlade-adekola-ada-ameh-in-trailer-for-new-comedy-movie/1e554hl[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ https://www.sunnewsonline.com/no-regret-having-a-child-at-14-ada-ameh/