Adalu (ounje)
Adalu je ohunje ti ogbajumo ni orile ede Naijiria. Adalu je ohunje ti won ma n se lati ara ewa ati agbado.
Adalu jẹ ounje kan ti á màn pe ni sóku dalè orilẹ-ede Naijiria ti a hún fí agbado ati ẹwa sè, o je onje to gbajumo laarin awọn Yoruba ati awọn Igbo.
Igbaradi
àtúnṣeA o se agbado ati ewa lọtọ ki a to da awon mejéjì pápọ . [1] A ó sí fi epo púpa, alubosa, ata ati iyọ si ko le ba dun.
A má n jé Adalu pelú ogede ati eja sisun.
Wo awon eleyi na
àtúnṣe- Ounje ni ilu Naijiria
- agbado didun
- Ewa aganyin, ounje Naijiria miiran ti a hún fí ewa se.
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://guardian.ng/life/how-to-make-adalu-beans-and-corn/