Adams Aliyu Ishiaku (ojoibi March 27, 1960) je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹjọ to n sójú àgbègbè Edu ni ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlè Kwara nibi to ti ṣíṣe gẹ́gẹ́ bi Alaga ìgbìmọ̀ fun ise àgbè ati oro àlùmọ́ọ́nì. [1] [2] [3]


Adams Aliyu Ishiaku
Member of the Kwara State House of Assembly
In office
18 March 2015 – 18 March 2019
Member of the Kwara State House of Assembly
from Edu Local Government
In office
18 March 2015 – 18 March 2019
ConstituencyEdu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹta 1960 (1960-03-27) (ọmọ ọdún 64)
Guye-Doko, Edu Local Government Kwara State Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (Nigeria)
Alma mater
Occupation
  • Politician

Awọn itọkasi

àtúnṣe