Adamu Gumba
Olóṣèlú
Adamu Gumba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Sen Adamu Gumba | |
---|---|
Aṣojú Gúúsù Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kẹjọ Ọdún 23 2010 | |
Asíwájú | Bala Mohammed |
Arọ́pò | Sen Ali Wakili |
Constituency | Gúúsù Bauchi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹ̀wá 1948 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Profession | Olóṣèlú |
Ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti Bauchi.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "SEN.GUMBA ADAMU IBRAHIM". National Assembly. Retrieved 2011-05-05.
- ↑ "2011: Woman activist solicits support for women aspirants". Daily Triumph. July 20, 2010. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2011-05-05.